Láyé Lyrics
- Genre:Afropop
- Year of Release:2024
Lyrics
Iwo Nikan Iwo Nikan Iwo Nikan ni Baba
Iwo Nikan Iwo Nikan ni Baba
Laye! Ko ma soba miran leyin Oluwa Laye!
Laye! Ko ma senikan ta le fi o we… Laye!
Laye! Iwonikan de lawimayehun Laye!
Baba lo le se Baba nikan lo le se o
Kijomole yin baba olorun loke ni Baba
Kijomole yin baba sebi Jehovah ni Baba…
Laye! Ko ma soba miran leyin Oluwa Laye!
Laye! Ko ma senikan ta le fi o we… Laye!
Laye! Iwonikan de lawimayehun Laye!
Ota lemilemi won o le bami
Sebi Iwo lo ko mi yo ni gbekun ota
Awimayehun Arugbo Ojo
Kabi o ko si Eleru Niyi
Laye! Ko ma soba miran leyin Oluwa Laye!
Laye! Ko ma senikan ta le fi o we… Laye!
Laye! Iwonikan de lawimayehun Laye!
Laye… Laye