As We Worship (Kábíyèsí) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
As We Worship (Kábíyèsí) - Tpeace Orekelewa
...
As We Worship (Kábíyèsí)
Fatusin Alexander O.O has added lyrics:
Kaabiyesi Olodumare Oba mi, Oba mi to dade, toba'ye kan ole de, Oba to joko Sorun to f'ile aye se itise Ree, Tayelolu ndupe.
Chorus: Kaabiyesi oo, Kaabiyesi-(Awa nse kaabiyesi oo)
Kaabiyesi ee o, Kaabiyesi-(fun Oba Ologo,fun Oba Oloore)
Onimoo togaju, Wo Ologbon julo
Eni to moni, mola mi, Kaabiyesi (twice) (Iwo Lo moni, mola mi)
Call in: As we worship
Chorus start immediately: As we worship in your presence, jeka r'aanu gba o, (niwaju Oba Ogo, Kaabiyesi Oba Imole)
Imisi ko wa, silekun itunu Re(Bi ase nyin O Oluwa, je a resi ayo, niwaju ite)
As we worship in your presence jeka r'aanu gba o, Imisi, r'ojo Ibukun le mi o. (twice)
Solo 1: Eni to fewa fun irawo, towa loju Orun(Against the building, to the stars, o f'ogo to da sewa, Tpeace je okan ninu won)
Eni to f'ogo to da sewa, ti mo je okan ninu won
Eni to moni, mola mi, Kaabiyesi (twice) (B.T.C)
Solo 2: E gb'osuba fun Oba aiku, Oba aisa
Oba to gbemi s'ejika wale, oun lolu sobidire
The Heavens declare the glory of God, won un seba re o, forever is with You Oluorun, Kaabiyesi (B.T.C)
Solo 3: Mo ka ninu Bibeli, Oni ka bere ao ri gba
Oni kaa kon lekun peee ao se
Oni kaa wa kiri, pee ari
Imisi, itunu, igbega, imole, ko ba le wa oo (twice)
The bridge: Womi ni iwaju re (wo mi Oluwa)
Womi ni iwaju re (emi kekere ni iwaju Re)
Womi ni iwaju re (Laisi O kini mo jamo)
Womi ni iwaju re (tani mi, tani iran mi)
r'ojo imisi, r'ojo ibukun lemi oo
The words come in as the people continue to sing (Womi ni iwaju re ..... solemnly)
Words:Ki Oluwa, ki O gb'ohun mi nigba iponju
Oruko Oluwa jakobu, ko daabo bo mi
Ki O ran iranlowo si mi lati'bi mimo wa
Ki O si tomi lehin, lati bi sioni wa
Ki O si ranti gbogbo ebo mi
Ebo ope ti mo un rusi lojojumo, ebo ayo, ebo ope, ki temi dire, ki temi dayo, ko korede, kin kola wa, kin korede, lojojumo.