![Blessed beads](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/11/06/2763ed1279bc4b38b48228c49523efe2H3000W3000_464_464.jpg)
Blessed beads Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
I'tesimuu bihabulillahi opa oluwa ni mo gbamu nitemi o
Chorus- Koromidun koleroju ma mu tesuba mi dani
Opa oluwa ti mo gba lopa Ashe ishe tinba ran ni o je o di dandan
Chorus - Adura Lofa mumini , Tesuba lorun ti o ranAdura Lowo
Adadi nbe Maje ki won ton e ounka to daju nbe gidi o
Chorus - Gba tesuba remu beere kosoun ti ko le gbe funni.