
Kabiyesi Re Baba Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2013
Lyrics
[ti:03 Kabiyesi Re Baba]
Kabiyesi re baba
Kabiyesi re omo
Kabiyesi re emi mimo
Idobale lan k’oba
Kabiyesi re baba
Kabiyesi re omo
Kabiyesi re emi mimo
Idobale lan k’oba x2
Kabiyesi re o baba
A wole niwaju re
Tewo gbope wa o baba
Idobale lan k’oba x2
Kabiyesi re baba
Kabiyesi re omo
Kabiyesi re emi mimo
Idobale lan k’oba
Kabiyesi re baba
Oba to wodi jherico
Tewo gbope wa o baba
Idobale lan k’oba x2
Kabiyesi re baba
Kabiyesi re omo
Kabiyesi re emi mimo
Idobale lan k’oba
Alagbara nla nla mowa juba re
Olorun to pe mi mo fori bale
Olorun to yan mi fe mo gbe o ga o
Mo kunle ese meji
Baba mi gbope
Alagbara nla nla mowa juba re
Olorun to pe mi mo gbe o ga o
Olorun to yan mi fe mo fori bale
Mo kunle ese meji
Baba mi gbope x3
Baba mi gbope
Baba mi gbope
Baba mi gbope
Baba mi gbope
Ayeraye baba mi gbope
Baba mi gbope
Meta lokan baba mi gbope o
Baba mi gbope
O gbe omo nija baba mi gbope
Baba mi gbope
Mo kunle ese meji
Baba mi gbope
Olorun ayeraye o mo se iba
Olorun ayeraye o mo se iba
Mo se iba toripe oun gbo adura
Olorun ayeraye o mo se iba
Olorun ayeraye o mo se iba
Mo se iba toripe oun gbo adura
Olorun metalokan mo se iba
Olorun metalokan mo se iba
Mo se iba toripe oun gbo adura
Olorun ayeraye o mo se iba
Olorun ayeraye o mo se iba
Mo se iba toripe oun gbo adura
Olorun babalola o mo se iba
Olorun oluojo o mo se iba
Mo se iba toripe oun gbo adura
Olorun ayeraye o mo se iba
Olorun ayeraye o mo se iba
Mo se iba toripe oun gbo adura
Olorun titilayo o mo se iba
Olorun jesus star o mo se iba
Mo se iba toripe oun gbo adura
Olorun ayeraye o mo se iba
Olorun ayeraye o mo se iba
Mo se iba toripe oun gbo adura
Oluwa mo gbe o ga o
Oluwa mo gbe o ga o
Awon orun bami yin o pe ose
Awon orun bami yin o pe ose
Oluwa mo gbe o ga o
Oluwa mo gbe o ga o
Awon orun bami yin o pe ose
Awon orun bami yin o pe ose
Oluwa mo gbe o ga o
Oluwa titilao gbe o ga o
Awon orun bami yin o pe ose
Awon orun bami yin o pe ose
Oluwa mo gbe o ga o
Oluwa mo gbe o ga o
Awon orun bami yin o pe ose
Awon orun bami yin o pe ose
Oluwa mo ma gbe o ga o
Awon orun bami yin o pe ose
Awon orun bami yin o pe ose
Oluwa mo gbe o ga o
Oluwa mo gbe o ga o
Awon orun bami yin o pe ose
Awon orun bami yin o pe ose