
ISESE Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
And what you're going to see is the setting up of Ifa temples
All around so that as people go to church on Sunday,
That's how they will also be going to IFA TEMPLES
BennyLee omo ofundunmade
Baba dudu ni baba wa oh
Aso funfun wa lara wa oh
Iroke lowo ileke lorun se o n niyi Omo awo
Ota o fe ka reru kaso tori Jesu o le demo
Ifa gbaye eru n ba pastor idamewa o le pemo
Ifa n gbaye o
Isese n gbayelo
Ogberi se bi o mo pe
Isese n gbayelo
Won gbogun gbote
Isese n gbayelo
Ati segun sete yi
Isese n gbayelo
Ifa lo tele Ado, Ifa lo telu osogbo
Ifa lo telu irele Ifa lo telu iwo
Ilorin pelu Ibadan titi lode ilu Bendel
Ifa lo tele ife taye fi gun o gege
Oba ti o bale josin ko gbera ko lo saudi
Rasheed to ba fe di Emir ko keru e lo bauchi
Ota o fe ka reru kaso tori Jesu o le demo
Ifa gbaye eru n ba pastor idamewa o le pemo
Ifa n gbaye o
Isese n gbayelo
Ogberi se bi o mo pe
Isese n gbayelo
Won gbogun gbote
Isese n gbayelo
Ati segun sete yi
Isese n gbayelo
Recently a former vice chancellor has been
Awarded a license to start Ifa university
He took his professorial dissertation on Ifa
So ohun gan ma n difa as a professor of Ifa
And has approached the Nigeria university commission
And they have given him license to start
Ifa n gbaye o
Isese n gbayelo
Ogberi se bi o mo pe
Isese n gbayelo
Won gbogun gbote
Isese n gbayelo
Ati segun sete yi
Isese n gbayelo