
ARIYA Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
This song is not currently available in your region.
Try the alternative versions below.
Alternative versions:
Lyrics
ARIYA - Ernieola Olusoga
...
E wole eh eh, e wole oo
e wole, e wole 2ce
(lift up your heads oh ye gates, come on somebody)
e wole eh eh, e wole oo
e wole, e wole 2ce
Iba re Jesu oba to ni ka ma be 2ce
Iba akoda iba aseda sebi Jesu l'olorun a seda gbogbo wa, Ogun orun a pe juba o kiba se (sobe)
Leyin re leyin re leyin re olorun iwo lo kan oo 3ce
Gba mi mo de olorun ogo gbami mo de onibu ore 2ce
Oluwa orun oun aiye iwo niyin ati ope ye fun, bawo laba ti fe o to onibu ore
(onibu ore, onibu ore e bawo laba ti fe o to onibu ore )
oya gba mi mo de olorun ogo gbami mo de onibu ore
Mo wa pade re oo, baba mo de oo aiye me dowo re ba mi tunse 2ce
Mi simi emi mimo, gbe mi wo alagbara 2ce
Ere emi ya mo fe lo ba won se 3ce
Adaba mimo ba lemi lejika.....
Eri oo ni mo wa sin oba eri oo ni mo wa wa 2ce
.....
Eri oo ni mo wa sin oba eri oo ni mo wa wa 3ce
Eri wole de e dide 2ce
Eyin a gbagba orun e dide 2ce
Eri agbo Jesu a tunde 4ce
Eyin a gbagba orun e dide 2ce
Fowo ase nla gbadura mi goke lo 2ce
Awa na re a fatewo gba ire 2ce
Awa na re omo oba 2ce
Ki lo nro, owo lo nro
ki lo nku, igbala nku bi ojo
Fi irawo kun irawo mi lo dey orun 2ce
Ariya nlo lo de orun ooo 2ce
Funfun ni lekeleke e yo mo 2ce
Lekeleke bami leke, eiye adaba ba mi lekeleke
..................?
Oni gangan ni Jesu yo soro mi dayo o 2ce
Mo gba ire 3ce
Oba to rewa ninu ola nla 2ce
..............?
Oluwa se bi o ti nse 4ce
Agbara baba ka 4ce
Oun loba oo, Jesu ma loba iye
Balogun nile balogun lode, oba a soro ma ye oba 4ce
Baba so mi d'apase 2ce
Jesu ma bo wa
Awon orun wo nsoro ogo re oo
Baba ndabira lolojumo
Iyanu loluwa 6ce
Wo baiye ti ri oba wa, wo baiye ti da ba wa tunse
Ounbo la to ke, oba wa
Efuli yah.......
Ologo logo ye gba ogo
To to iba re oo ..........