Oriade Lyrics
- Genre:Afrobeat
- Year of Release:2024
Lyrics
Oriade - Portable
...
Portable (Oriade) King
E dọbalẹ f'oriade
E sa Ti ri olowo layemo
Ori 'n fọ yin èlò paracetamol
ẹdọ 'n ro yin elo gun jedi
Toba de Lafenwa
Owo lan'wa
omo ẹgba kokin'gba gbakugba
kofi sanwo Alao
kosogun ofe lọdọ babaláwo
Èsọ fun Durodola
omo ballers n bolowo lọ
Wọn ní mo shogun owo
Owo lonma fin' se pese owo
Kosogun ofe lọdọ babaláwo
Wọn ní mo shogun okiki
Eyin naà elọ shogun osi
Osi ará tama rayo
Loje kon ma so rubbish
Gbafun muri ni gbafun padà
O'n t moba sọ ni kaye magba
E dọbalẹ f'oriade
E sa Ti ri olowo layemo
ori 'n fọ yin èlò paracetamol
ẹdọ 'n ro yin elogun Jedi
Toba de Lafenwa
Owo lan'wa
Omo ẹgba kokin'gba gbakugba o
Kofi sanwo Alao
kosogun ofe lọdọ babaláwo
Gbélé pawo oji lo gbowo
Nobody is clean the stain is different
For every level there is a different devil
Stain prepared for a new level, with a different devil
They no dey celebrate a failure
Am a winner am not a failure
They no dey celebrate a failure
E dọbalẹ f'oriade
E sa Ti ri olowo layemo
ori 'n fọ yin èlò paracetamol
ẹdọ 'n ro yin elogun Jedi
Toba de Lafenwa
Owo lan'wa
omo ẹgba kokin'gba gbakugba
kofi sanwo Alao
kosogun ofe lọdọ babaláwo
eso fun Durodola
omo ballers n bolowo lọ
NILU
Shocker lose beat