![Salaro](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/00/1F/rBEeNFfvAoaAbuevAACdJotyec8705.jpg)
Salaro Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2016
Lyrics
Mutum
Say baba
CDQ yeh yeh
Masterkraft on the beat
Yeh yeh.
Woss
Ijo awon to Salaro
Woss ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss s’o ti ye?
Ijo awon to Salaro
Ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss s’o ti ye?
Ijo awon to Salaro
Woss ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss s’o ti ye?
Ijo awon to Salaro
Ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss s’o ti ye?
Makan-makan l’oye n kan
MC gbagbe hammer; ko se e kan n
Ma a ba won pelu obo jawura
E ye pe Yaya Toure f’emi l’Akon
Sade: o kare
Se pe iwo na ma n de’bi?
T’o ba wa di Sunday, t’o ba ri mi ni church
Wa a ma se bi pe o da mo
Hello, brother Kamo; e ka’ju
E lo gba’le si after Mile-2
E gbo’ju
E ti ye isale wo; e ma ri n’t’o n ke n be
Koda, a tun ma kin i wa
Leyin k’e so’ju nu; k’e f’opa rin
Wa a; je k’a lepo- Victoria Kimani
O sa mo Davidi?
Ijo t’o jo ninu Bibu l’ojo si
O ye Oloun
Ijo awon to Salaro
Woss; ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss; s’o ti ye?
Ijo awon to Salaro
Ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss; s’o ti ye?
Ijo awon to Salaro
Woss; ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss; s’o ti ye?
Ijo awon to Salaro
Ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss; s’o ti ye?
Eku ma je Sese
A a n disturb, bi i Tatakuku elero
Eyin Mikano, awa ni Tiger
I better my neighbour- Ishola Kuku
{Wo’bi}
CDQ t’o jina; ba n m’Origin nah
Ibi t’a a ti wa jina a
Woss; Shola l’oruko mi o
Stubborn niso; ma ro pe o le ti mi
Omo mofe yato s’omo jagba
Mo fe f’erigi s’aye ti n ba d’agba
Star l’omo, and am going ragga
Ayedoro a pon bo n salanga
Salary wo’le, mo jo Salaro
{Woss}
Alawi wo’le, mo jo Salaro
{Woss}
Ise kala wo’le, mo jo Salaro
T’akata ba tun sa wa, ma a jo Salaro
Ijo awon to Salaro
Woss; ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss; s’o ti ye?
Ijo awon to Salaro
Ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss; s’o ti ye?
Ijo awon to Salaro
Woss; ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss; s’o ti ye?
Ijo awon to Salaro
Ma lo goo
Ijo awon to Salaro
Woss; s’o ti ye?
Oyekan
Wo’bi; woss
Sekelebebe; ma lo gbankuru gbankuru bebe
==Shayman the mix==
Woss; ola a kunfayakun
Alomo, daagun
Wo’bi; ma lo saagun, segaa
Ose; t’o Salaro