
Abetilujarabiajere Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
B'oju olomo oto
Lowo cruel demeanors
Ta lo n sike omo ni tosi ile
Bi Baba jade oh bi Mama Jade
Abetilujara bi Ajere
Abiamo Jesu Oba Iye
Emi re n'bi oh eh eh
Jesus Son of David Eze mo ah ha ah ha
R'ogba yimika ah nibi gbo gbo oh
Abetilujara bi Ajere
Abiamo Jesu Oba Iye
Abetilujara bi Ajere
Abiamo Jesu Olowo gbogboro
Abetilujara bi Ajere
Abiamo Jesu Oba Iye
Abetilujara bi Ajere
Abiamo Jesu Olowo gbogboro
Mo je reledumare fin
Oba Owa
Oba Owo
Oba Owawawowo
Iyalaya Goliath
O se gbugbugbugbu
O di eti Pharaoh
Akobi ninu awon oku oh
Oluwa Iye
Oluwa Iyin
Oluwa Iyi
Oluwa Eye
Kabiyesi Oh