
The Price Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
This song is not currently available in your region.
Try the alternative versions below.
Alternative versions:
Lyrics
The Price - BBO
...
Hallelujah
(Speaking in tongues )
Alanu eda Ogo ni fun oruko yin
Olorun to ni aye ni ika woo
Oba to n sekun derin olorun
Ye o e ooo
Tongues!!!!
Iwo ton ma tun ori alasunwo se olorun
Aaagbe fun e sir
Aaagbe fun e o
Aaa gbe fun e
Aaagbe fun e o
E o
Oo
Agbe fun e
Eoo
Baba jesu
Mo gbe fun e
Iwo to n ma fun ole ni agbara oo
mo gbe fun e
E o
Ah
Ago awoye yi gba alejo
Ago awoye yi gba alejo
O gba alejo
Akoda aye olokun ajoba
Ile yi gba alejo
O gba alejo
Akoda aye aseda odun
Ehn ile yi gba aaa
Ee
O gba alejo olorun
Tongues!!!
Ahh
Ilu yii gba alejo oo
Ilu yii gba alejo
O gba alejo
E ni to fi omo sinu wundia lojosi
E o ooo
Oo o
Eeee o ah ah
Ona to ni koko to ile aye lowo
Toruń mbe lodo re oo
Mogbe fun o
Iwo to ma n silekun ojo gbogbo
Ninu orun lohun ngbe olorun
O den shey bo se wun e o
E Ola ba ma mo oo
Decision re ni oo olorun
Bi o si ni mo oo
Baba ta lo ba o
Bi olorun
Agbe fun e
Tile