Dont Touch Me ft. Djecomon Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Dont Touch Me ft. Djecomon - Legend Beatz
...
Written by Gentle_beeboy
........
Djecomon 24
eyin lè sọ Pe mio mon orin kọ
Orin alubarika
Orin tí modẹ n'kọ ni mofi jade gan
Orin alubarika
Awon omo to mo orin kọ kan bere sí n'makun kin'ma gbọ
Wahala kan lode óo
Eeyy ẹ panumo ọmọ l'ogo ni n'dun
Tin'nbà dun oyẹ kẹ panumo
MIOFỌ
Oyẹ kon gbọ l'amerika
Won fẹ gbọ nkan ti mó man sọ
Emi l'omo tonsọ
Kilo waa kilo fẹ
Ẹlẹdàá mi ma má sùn
Orí mi ma gba Abode
Orí mí ma ka abuku
Kilo wàá kilo fẹ
(Chorus)
Don't touch me
Ẹlẹdàá mi ma má sùn
Don't touch me
Orí mí ma gba Abode
Don't touch me
Orí mí ma ka abuku
Don't touch me
E panumo ke duro
Hummm.......
Abẹrẹ ni mi
Mo kéré mio kín ṣe mimi fún adiyè
Ẹfẹ danwo
T'eba fẹ danwo
Ma má jẹ kó yé pe ata ni mi
Mi'o kín ṣe ẹgbẹ ojú óo
Emi juba ki'n to bẹrẹ si'n ma korin
Orin biza biza
Kilo wàá kilo fẹ
Ẹlẹdàá mi ma má sùn
Orí mí ma gba Abode
Orí mí ma ka abuku
Kilo wàá kilo fẹ
(Chorus)
Don't touch me
Ẹlẹdàá mi ma má sùn
Don't touch me
Orí mí ma gba Abode
Don't touch me
Orí mí ma ka abuku
Don't touch me
( FADE MUSIC )
KILO WÀÁ KILO FE
ẸLẸDÀÁ MI MA MÁ SÙN
ORÍ MI MA GBA ABODE
ORÍ MI MA KÁ ABUKU
by @gentle_beebo