Worship Medley Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Oluwa, Oluwa wa
Oluwa, Oluwa wa
Oruko re ti n'iyin to
Oluwa, Oluwa wa
Oluwa, Oluwa wa
Oruko re ti n'iyin to
Oluwa, Oluwa wa
Oluwa, Oluwa wa
Oruko re ti n'iyin to
Oluwa, Oluwa wa
Oluwa, Oluwa wa
Oruko re ti n'iyin to
Awa dupe o Baba
Awa dupe o Omo
Emi mimo e se
T'ire ni ogo
Awa dupe o Baba
Awa dupe o Omo
Emi mimo e se
T'ire ni ogo
Awa dupe o Baba
Awa dupe o Omo
Emi mimo e se
T'ire ni ogo
Somebody say grace, grace
Ore ofe sha ni o
Somebody say mercy, mercy
Aanu ni mo ri gba o