
Jesu Loba Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Jesu Loba - Temitope Akanbi
...
Jesu Loba
ohun loba
Jesu Loba
ohun loba
ehhh...
Jesu Loba lórí ayé mi o
Jesu Loba, lórí ilẹ mi o
ohun tó ba to so,
kòsí eda to lẹ yí padà
ohun tó ba ti 'se
kòsí eda to lẹ yí padà
Jesu Loba, lori Aye mi o
Messiah Loba lórí ilẹ mi
ohun tó ba ti so,
kó mò sí ẹdá to lẹ yí padà
O somi d'omo
kó má sì Bàbá bi're
O somi d'omo
kó má sì Ọlọrun bi're
Yeh... Jesu Loba lórí ayé mi o
Jésù Lóba
ohun loba
Jesu Loba
ohun loba
Yehh ehhh...
mo fẹ kọ gbà loba
sínú ayé rẹ o
mo fẹ kọ gbà loba
sínú ilé rè o
to BA ti gbà loba
Gbogbo òke ìṣòro yeni
a di petele o
Oni tani iwo Oke
ni waju serubabel
to ba ti gbà lóba
ninu Ile Re o
gbogbo òke ìṣòro yen
A di petele o
To BA boju wẹ yin
o tun ri mo o
mo fẹ kọ gbà loba Si nu ayé rẹ o( Je...
Jesu Loba nínú ayé mi óo
Jesu Loba
ohun loba
Jesu Loba
ohun loba
Ohhh ....
Jesu Loba o
ohun loba lórí ayé mi ehh
Jesu Loba nah..
ohun loba lórí