
Unmerited Favour Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Unmerited Favour - Kemi Ara
...
chmi o mose
mo kan ri aanu GBA ni
ogbogo fole mi
oluwa ose
mio pe be ni mi ode ye
mio moyan
mio tun ni connection
awon kan Le se ju mi
aanu lo mu mi tayo
bio ba SI toluwa to faanu WA mi ri
mi o moseeeee
chr..
aalara me riri
ofaye mi dara
ose ohun teyan o lese oforo mi jota loju
ohun ni ohun ko lariwo tonta mi npa
baba mi lo bami se
eniyan ko lo se
ch..
emi ni definition aanu unmerited favor lo UN sise
ewo mi Keri Anu
ewo mi Keri oore ofe
ibi teyan ole mimu de
aanu oluwa lomimu debee
connetion Okan mi o tun n
aanu oluwa lo ba mi seee
ch...
oluwa oseeee
rep.,...
baba lo nse eniyan ko lo se Yi ooo
all...oluwa oseeeee
baba lo se eniyan ko lo se yiooo
all.... oluwa ose
Toba jeniyan ni won tima sirengun
all...oluwa ose
aanu Mori GBA emi ti n mi o je n ikankan
all.... oluwa ose