![My Father My Father](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/03/19/3a38915d6427456cabbd7fff61d20221_464_464.jpg)
My Father My Father Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2023
Lyrics
My Father My Father - Barry Jhay
...
Oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh
Oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh, yea-yea
(Mad-Madaroad)
Oh-oh-oh-oh-oh-yea-uh-uh-oh
Oh-oh-oh-uh-uh
Yea, eh-eh
Say, I don't force it
I just let the Spirit lead, 'cause I know
Yes, I know You are with me all the way
My Father, My Father, Ọlọrun ti ko kí ń yipò padà
Ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lowa, ìwọ nìkan ní mo gbẹkẹmile o, ah-ah (ẹru ògo rẹ ńbámí)
Ẹlẹwa Ògo, hm, Àdàbà Mímọ, jọwọ, bale mí o, oh-oh (emi ọmọ rẹ ree)
Mo tún dúró síwájú rẹ bí mo ṣe má ńṣe
Ẹmí-Mímọ, jọwọ, wá gbé mí fo oo
Mo fẹ ga nínú wọn (gbà mí gbọ)
Má ṣe gbàrà lewọn, má ṣe gbẹkẹle'nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀le ènìyàn asán bansa, ye-ye o
Má ṣe gbàrà lewọn, dákun, má ṣe gbẹkẹle'nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀le ènìyàn asán bansa, yeye-oh
Ìrìn yí mọọ, má lọ lofo, ní mo ṣe d'ẹsẹ Ọlọ́run mí mú o, uh
(Ní mo ṣe gbà Ọlọ́run mí mú ṣinṣin)
Bí Olùwà ṣe ń ṣ'ọla ìyẹn nínú ọlá àt'ayọ
Bẹ ní yí o tún ṣ'ògo, ohh, Ọlọrun mí ògo
My Father, My Father, Ọlọrun ti ko kí ń yipò padà
Ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lowa, ìwọ nìkan ní mo gbẹkẹmile o, ah-ah (ẹru ògo rẹ ńbámí)
Ẹlẹwa Ògo, hm, Àdàbà Mímọ, jọwọ, bale mí o, oh-oh (emi ọmọ rẹ ree)
Mo tún dúró síwájú rẹ bí mo ṣe má ńṣe
Ẹmí-Mímọ, jọwọ, wá gbé mí fo oo
Mo fẹ ga nínú wọn (gbà mí gbọ)
Má ṣe gbàrà lewọn, má ṣe gbẹkẹle'nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀le ènìyàn asán bansa, ye-ye o
Má ṣe gbàrà lewọn, dákun, má ṣe gbẹkẹle'nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀le ènìyàn asán bansa, ye-eh-oh