![Ma So Pe](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/03/18/0f583f9801d548cab79886344ac9bb2a_464_464.jpg)
Ma So Pe Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2020
Lyrics
Ma So Pe - Barry Jhay
...
Mo má dúpẹ' Bàbá ooo
Elẹrú mí yín o (it's Bizzouch)
Mo má dúpẹ', oo-eh
Oii-nih
Baba, I see
I see the weather too coming through for me
With Your power, I dey see front oo, eh-eh You do me wetin, nobody fit to do-do for me Oii-nih
Oh-oh Orí adé ló ṣé mí oo, oh na-na Ṣé bí 'wo lónì ńmá j'ọba, eh-ee Orí mí tètè lá, k'orí ọlọlá máà pé ẹ rán níṣẹ̀ o Ẹ'dá mí tètè lá, k'ẹ'dá ọlọ́lá máà pé ẹ o
Mà ṣọ'pẹ
F'ore tó ṣé láyé mí, òpọ púpọ', ye o
Ọba ayérayé, ráyé
Mà ṣọ'pẹ (ooh-)
F'ore tó ṣé láyé mí o, opọ púpọ', ye o
Ọba ayérayé, ráyé
Say me, I don't know, know
Say me, I no know, know
Daddy, why You love me so? Walahi
Why You love me so oo?
I don't know, I no know
Me,Ino know o
Why you love me so oh?
Why you love me so oo? (Oii-nih)
Bàbá Mímọ' o
Orí adé ló ṣé mí oo, eh-eh-eh, ee
Ṣébí 'wo lónì ńmá jọba
Orí mí tètè lá,k'orí ọlọ́lá má pé ẹ rán níṣẹ̀ K'ẹda mí tètè lá, k'ẹda ọlọ́lá má pé ẹ o
Mà ṣọ'pẹ
F'ore tó ṣé láyé mi, o pọ púpọ', ye oo
Ọba ayérayé, ráyé
Mà ṣọ'pẹ (ooh-)
F'ore tó ṣé láyé mi o, o pọ púpọ', ye o
Ọba ayérayé, ráyé, 'ayé