Atobiju ft. Adeyinka Alaseyori Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2018
Lyrics
Atobiju ft. Adeyinka Alaseyori - Ola
...
Chorus Olorun wa, Ayeraye mo gbe o ga o Mimo mimo Atobiju Eyin nikan l’ogo ola ye fun Verse 1 – Ola From the rising of the sun Unto it’s going down Mi o r’eni to jo o Ti mole fi o we Ologo ara nla, t’oni gbogbo ogo Ashiwere wipe, Olorun k’osi N’oje ba won so, Nitori moti mo o Olola Ni JESU mi, ewa re k’oja oye Baba o ni bebe, sa ma t’oju mi lo Olorun Baba Agba Oye. Chorus Olorun wa, Ayeraye mo gbe o ga o Mimo mimo Atobiju Eyin nikan l’ogo ola ye fun Adeyinka o ya now Verse 2 – Adeyinka Alaseyori Iyin re o le dawo duro, lenu MI Oluwa Iba re Akoda Aye, Aseda l’ode orun Asaju Ogun la lo, Akehin Ogun l’oje Paripari Ola, Alebe ilu a sasi O da wa si, O pa wa mo Olore e e e Iwonikan l’awa gbe ga Iwonikan l’awa pe bo From the beginning of our lives Till this very moment Eh Eh Eh, You’ve been faithful Ever faithful God Chorus Olorun wa, Ayeraye mo gbe o ga o Mimo mimo Atobiju Eyin nikan l’ogo ola ye fun Drums Interlude Bridge Call: E ba n’kira, E ba n’kira, E ba n’kira fun Response: E ba n’kira 3x Olori Aye gbogbo – E ba n’kira fun T’omu riri jade ninu airi – E ba n’kira fun Orisun Ayomi l’oje – E ba n’kira fun O ni ole ojo merin dide Baba – E ba n’kira fun O mu omi jade lati inu apata – E ba n’kira fun O rin Lori omi, sibe ko ri – E ba n’kira fun Ake to bo sinu omi, igi lofi gbe jade – E ba n’kira fun JESU Olugbala o wo odi Jericho – E ba n’kira fun Talaka wa Lo jeun pelu awon Oba – E ba n’kira fun Ari na Ari Lo wa di ohun igbagbe – E ba n’kira fun Agan ojo pipe, won di Iya olomo – E ba n’kira fun K’osi ohun to s’oro se fun Olorun Bami – E ba n’kira fun Ah Ah ATOBIJU E ba n’kira fun.