OMO MI Lyrics
- Genre:Acoustic
- Year of Release:2024
Lyrics
OMO MI - Awoshifila
...
.......
hmmm hmm
olohun bami wo awon omo mi
oba olohun bami wo awon omo mi
ma jen foju sunkun omo oo
ola alubarika ko to egbee
hum Omo mi ni gilaasi mi ooooo×2
Omo mi ni gilaasi ti mo fin woju
Omo mi ni ti mo Fi wo ran re
kaye mafo gilaasi mi
wola lu barika ko to egbe
Kodagba ko juu baba e loo
kodagba ko juu mama e loo
olohun jeko lalubarika kotegbe