
Odun nba ku Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2024
Lyrics
Odun nba ku - Teledalase
...
óyeku mo bá ó mu lè má ma shẹy damì
ìnu bìbì èru ní n pa èru édò fufu ìwofa nì pà ìwófa
adifa fun ofua niìgba tí n bẹ la rìn òtá ayé bì ku. ba n se gbe mi pa oto ni ki oyè ki o ma sa mi si. bi arun sé egbe mi se oto ni oyé ko masa mi si gbò gbó alawe obi ni iku n pa oto la yo ofu a si. ìku ma pa awo mo iku ye lori àwò ọto
la yo ofu á óbì si, ìku má wó mó ìku ye lórì áwò.
Óyeku mó ba ó mule mama se dami ìku remì kete iku ye lorí mí. ìku mama sé ya lodede mí ori mì ma se gbá ó2ce Ó dun n ba ku ma a raso, Ódun n ba ku ma a raso odun n ba ku oo, n o wọ sayan odun n ba ku ó n ó mómó yò òòòò... 2ce
ódun n ba ku n ó ma sógè, Ódun n ba ku! o ma fi ìle pon otì odun n ba ku ó n fi ona roka n ọ yọ sese2ce Ódun ba ku o!2ce n o yo sese.2ce
kin pe bi pepe tin pe kí n gbó kín tò, ki n fi ówọ pe wu ki fí eri gì jọ bì, kí ku re mì kete oooo ìku re mì kete óóó. ìku ma ma se ya ló dede mi ooo. iku ye lori mi ooo. 2ce
Óyèku mó ba ó mule mama se dami òbá má má sẹ dá mììì ooo. Ódun n bá ku óóóó. má rá áso má bórí2ce máru bò ópè. ódun n ba ku òòò! n o mo yọ n ó mòmò yo! ìku re mì kètè iku yé lorí mì2ce óyẹku mo bá ó mulẹ mámá sé dámì óóó! 2ce iku mapa awó mó iku yé lórí awó.