Ara Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Olowo Nsoro tani talika to n j'enu wuye wuye
Owo lo n mu ni maa b'eyan maa bere maa se kube kube
Olowo Nsoro tani talika to n j'enu wuye wuye
Owo lo n mu ni maa b'eyan maa bere maa se kube kube
Iba se pe mo l'owo l'owo
Maa ti k'ole bi ogun, ra motor bi ogbon
Maa ti b'imo lo rere, omo rere ere rere
Ara Nba da, ara Nba da
Ara Nba da, owo o je oh, owo o je oh
Apekanuko
Ara Nba da, ara Nba da
Ara Nba da, owo o je oh, owo o je oh
Apekanuko
Iya lo n je mi mo e ri
Owo lo n je mo ba e tan
Ewa wo eni won o fe jiri
O wa d'eni atanna wo
Baba fun mi l'owo l'owo
Maa se fun mi l'owo l'orun
Baba maa f'owo s'ore mi
Wa f'owo s'eru mi
So that anywhere I want I go fit send ham go there
Ye eeeeh ooh
Olowo Nsoro tani talika to n j'enu wuye wuye
Owo lo n mu ni maa b'eyan maa bere maa se kube kube
Olowo Nsoro tani talika to n j'enu wuye wuye
Owo lo n mu ni maa b'eyan maa bere maa se kube kube
Iba se pe mo l'owo l'owo
Maa ti k'ole bi ogun, ra motor bi ogbon
Maa ti b'imo lo rere, omo rere ere rere
Ara Nba da, ara Nba da
Ara Nba da, owo o je oh, owo o je oh
Apekanuko
Ara Nba da, ara Nba da
Ara Nba da, owo o je oh, owo o je oh
Apekanuko
Baba gbo adura mi
Olorun Oba si ju anu wo mi oh, tori
Mo fe ra ile ni Cali
Ki n maa jaiye ni Paris
Ferrari, Bentley, Baba mo fe maa fi s'ese rin
Ki n jaiye tan n Miami
Ki n gba Abi Dhabi lo
Bellagio in Vegas mo ti fe se summer mi