
Tire Ni Lyrics
- Genre:Soul
- Year of Release:2024
Lyrics
Tire Ni - Rebecca
...
Aye mi o wa lowo re oluwa o
Aye mi o wa lowo re
Aye mi o wa lowo re oluwa o
Aye mi tire ni
Ni diduro mo duro
Mo duro ti o oluwa
Iseti aso re iye lo je
Igbala ofe to mu wa
Lomu aye mi dara
Aye mi tire ni
Jeki n lema sin o oluwa
Fun mi nipa ati agbara
Maje kohun aye bori Okan mi
Ife re oluwa ni mofe mase, nitori
Ni diduro mo duro
Mo duro ti o oluwa
Iseti aso re iye lo je
Igbala ofe to mu wa
Lomu aye mi dara
Aye mi tire ni
Aye mi tire ni Jesu(tire ni Jesu)
Oro re fitila fun ese mi( ati imole si ona)
Ati imole Sona mi(Jesu)
Jesu( lolugbeja)
Lolugbeja mi(aye mi)
Aye mi o wa lowo re oluwa o( tire ni Jesu)
Aye mi o wa lowo re (ise mi dowo re)
Aye mi o wa lowo re oluwa o (o dowo re ba odowo re baba)
Aye mi tire ni (aye mi)
Ni diduro mo duro
Mo duro ti o oluwa
Iseti aso re iye lo je
Igbala ofe to mu wa
Lomu aye mi dara
Aye mi tire ni