Santari Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2023
Lyrics
Ibo leti ko awon Omo eleyi wole ewo nkan tanfi shedi iru awon idi buruku wo leleyi malo woran idi ko lo da mi ni igbonu mo nkan ton se oo
Serious relationship I'm not in for the shit
Santari dedegbo
Matilo
Ajoke kere loju santari baba epon
Maami ema ti lor Omopo tema pon
Ile aye ole omonuaye lon mayele
Lagege wajiya wafere ge
Toko tile owa sope Ori uber
Bori Uber kogbokada
Bo rokada ko fese shaa
Ninu leki anjayepa
Ninu Quilux andomopa
Ninu lorlor anlowonpa
Ninu London anjayelo
Ninu leki anjayepa
Ninu Quilux andomopa
Ninu lorlor anlowonpa
Ninu London anjayelo
Tundeednut post mi
Shen shere ni abi enshiere
Iwo ati tanibniwaju tani
Wobi
Criminal por tema ko
Fowo offering gbolosho
Ajoke jor bami Jo
Oni le jo toba darugbo
Serious relationship I'm not in for the shit
Santari dedegbo
Matilo
Ajoke kere loju santari baba epon
Maami ema ti lo Omo po tema pon
Ile aye ole omonuaye lon mayele
Lagege wajiya wafere ge
Toko tile owa sope Ori uber
Bori Uber kogbokada
Bo rokada ko fese shaa
Ninu leki anjayepa
Ninu Quilux andomopa
Ninu lorlor anlowonpa
Ninu London anjayelo
Ninu leki anjayepa
Ninu Quilux andomopa
Ninu lorlor anlowonpa
Ninu London anjayelo
Abotan abotan ebo Ko lor far
Ogbami lalejo mio jeyan miode jeresi
Jigan jigan handicap esemi otole farabale
RIP my brother mohbad
Everybody de mope o bad
Imole Imole owale ooyorjo
Omo iyami sunre
Ninu leki anjayepa
Ninu Quilux andomopa
Ninu lorlor anlowonpa
Ninu London anjayelo
Ahhh anjayepa