TEMIDIRE Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
TEMIDIRE - Taiwoamen
...
TEMIDIRE imole Mi ntan lojo jumo
Odire lojo gbogbo odire nigba gbogbo, ewomi etunmiwo, oromitope otun ju ope lor
Say !! Say !! Say !!!
Taiwoamen !!! Oya now ..!
Ero to ta ro lori Mi Ko se, moti ni Jesu òkan Mi ti balé modupe o Jesu fun Anu ti mò nri eh eh eh..!
Chorus; TEMIDIRE imole Mi ntan lojo jumo,ero to ta ro lori Mi Ko se,moti ni Jesu òkan Mi ti balé,modupe o Jesu fun Anu ti mò nri.
Verse 1; Amen, wòn fe dami duro sugbon Olorun Ogba, wòn gbe igi Dina mi sugbon ayé ope pada yo, ibi ayé foju si ona mi Ogba be , modupe o Jesu fun Anu ti mo nri .. sorosoke !!
Chorus; TEMIDIRE imole Mi ntan lojo jumo,ero to ta ro lori Mi Ko se,moti ni Jesu òkan Mi ti balé,modupe o Jesu fun Anu ti mò nri.
Verse 2; Gbo, eniyan lopa ri Jesu Mi ni mo sese bere, koma so wun to le ti Jesu Mi Ko le se funmi, awa leni te ropin to pada wa di ogo pataki, modupe o Jesu fun Anu ti mo nri , Amen..!
Chorus; TEMIDIRE imole Mi ntan lojo jumo,ero to ta ro lori Mi Ko se,moti ni Jesu òkan Mi ti balé,modupe o Jesu fun Anu ti mò nri.
Verse 3; Shò mo pe 1 + 1 =2 Olorun is true, 5+5 =10 emi o le té o,, and I don get assurance say my own go better, cus emi ti mo Olorun moti mò way Mi niyehn Aamen…!!