OBA KU Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Ready know
Ye ye ye
Hummmmm
Listen to my vocal
Dont be sober
Life is a market
We all are buyer
Buying something diff it a sin
In this market that we are inn
Oba kekere
Du ile aye
So si ile aye
Erupe n je oba ni ori o
But ko ye won pe
Ile aye asan
Imule mofo ni ore mi
Erupe nje erupe sanra ah ah ah
Awaye maku kan ko sio
Olorun nikan ni orio
Erupe apada fi erupe bora
Laisi ani oh
Ore mawa aye moya o
Oja lo wa ra oh
Dema sora o
Fi igbagbo gbe oh
Ajo laye se otiye
Oba kekere loje ni ile aye
Oba a ku
Oba a kuu
Eyin nikan loma kuu
Oba mimo togaju gan ni
Oba ti kin kuu
Oba a ku
Oba a kuu oh oh
Eyi nikan loma kuu
Oba mimo to gaju ganni
Oba ti kin ku ye he