
Melo ft. Chidinma & Oritse Femi Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2014
Lyrics
Haha vj adams
Melo musical taliban number 1
Melo melo melo
Ile melo lefe ni kari
Oko melo lefe ni kari
Ohun gbogbo owo ori mani
Omo labere orin labi
Melo melo melo melo
Melo melo melo melo
Melo oya e mellow
Talofe gbemu eyin melo
Atiwolede eyin smellows
Won fe binu ori won ma penbe
Woni wonpe ati je tete
Talosope omo elo se jeje
Teba tiri won nise lema kanle
Awa tijeun lo elo senpe a o raye rubbish
Ile melo lefe ni kari
Oko melo lefe ni kari
Ohun gbogbo owo ori mani
Omo labere orin labi
Melo melo melo melo
Melo melo melo melo
Melo moleka lore ofe oluwa
Anu re topo atore tose funwa
Bimo se jaye ki n se mummy mi
Bimo se lo soke ki sawoto daddy mi
Ogbagba tin gba ni gbani lowo iku
Otun gbani lowo arun won n binu ori
Ha won fe boba muti
Ile melo lefe ni kari
Oko melo lefe ni kari
Ohun gbogbo owo ori mani
Omo labere orin labi
Melo melo melo melo
Melo melo melo melo
Eye maro ni pin eyin abinu eni
Aimoye nkan toju tiri nile elebi
Ejigbo nile komo to keso rode
Awon adams okere oun gan tiba won gbe
Atilo mowon lowo atilo mowom lowo
Ajiya kato joro ajiya kato joro
Ati lo mowon lowo ajiya kato jor
Ile melo lefe ni kari
Oko melo lefe ni kari
Ohun gbogbo owo ori mani
Omo labere orin labi
Melo melo melo melo
Melo melo melo melo
Ao taraka kato jeun
Ise owo yen oti dowun iyalenu
E sama juru bebe nlo omode iwoyi e saye lo
Jeje jeje laye
Asise sise kato jaye
Nisiyin owo n circulate msn a ti penetrate
Ile melo lefe ni kari
Oko melo lefe ni kari
Ohun gbogbo owo ori mani
Omo labere orin labi
Melo melo melo melo
Melo melo melo melo