![HALLELUYAH](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/12/08/3f8d7e3ac7454b0aa7e309539610a539_464_464.jpg)
HALLELUYAH Lyrics
- Genre:Reggae
- Year of Release:2023
Lyrics
HALLELUYAH - OLUWASEUN OLAOLUWA
...
Hallelujah, Hallelujah,
Hallelujah, Hallelujah,
Hallelujah
(E bami ko lorin)
Hallelujah, Hallelujah, (Halleluyah)
Hallelujah, Hallelujah,
Hallelujah
Hallelujah, Hallelujah,
Hallelujah, Hallelujah,
Hallelujah
(Orin Isegun)
Hallelujah, (Hallelujah) Hallelujah, (Hallelujah)
Hallelujah, Hallelujah,
Hallelujah
Oro kan wa ti ko yipada ri
Oro Oruko yii kikida Iyaanu ni
Iyebiye loje O koja oye eniyan
Oun sa lafi ni Access si Baba l'Orun
Oruko kan wa to n so oku dalaye
Oruko yi le iso agbara ni
Imole lo muwa onirobinuje dalayo
A da ounde sile loruko yi kan naa
(Oruko Iyanu)
Jesu Jesu (Jesu)
Jesu Jesu
Jesu
(Oruko Iyanu)
Jesu (Jesu Jesu) Jesu
Jesu Jesu
Jesu
Call: Hallelujah ko ni tan nile re
Res: Wa a korin, korin, korin Ami Hallelujah
Call: Orin Hallelujah ko ni tan lenu awa
Res: A o korin, korin, korin Ami Hallelujah
Call: Orin isegun koni tan lodede mi
Res: Ma korin, korin, korin Amin Hallelujah
Hallelujah, (Halleluyah) Hallelujah, (Halleluyah)
Hallelujah, Hallelujah,
Hallelujah
(Orin Isegun)
Hallelujah, Hallelujah, (Halleluyah)
Hallelujah, Hallelujah,
Hallelujah