![Ilekun Ayo](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/07/05/b62e89d6cb2d4a27ade91929a79aeaa6_464_464.jpg)
Ilekun Ayo Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Oba to ni kokoro to nsi to nti
Jesu to ni kokoro to nsi to nti
Si 'lekun ayo mi o
Ti 'lekun mo 'banuje
Oba to ni kokoro to nsi to nti
Oba to ni kokoro to nsi to nti
Jesu to ni kokoro to nsi to nti
Si 'lekun ayo mi o
Ti 'lekun mo 'banuje
Oba to ni kokoro to nsi to nti
Ilèkùn Aanu ma si
Ilèkùn igbega mi o e ma si
Ilèkùn ire mi o, Oya e si
Ilèkùn igbe s'oke mi o Oya e si
Ilèkùn Omo
Ilèkùn ire
Ilèkùn Ile
Ilèkùn Ayò ooo
Oba to ni kokoro to nsi to nti
Jesu to ni kokoro to nsi to nti
Si 'lekun ayo mi o
Ti 'lekun mo 'banuje
Oba to ni kokoro to nsi to nti
Ilèkùn ibinu
Ilèkùn Ofo e ma ti
Ilèkùn ifa s'eyin Lori aye mi
Ema tiwon
Ilèkùn ti koyemi ema ti
Ilèkùn to ndi mi lowo
Ema ti won
Jesu to ni kokoro to nsi to nti
Oba to ni kokoro to nsi to nti
Jesu to ni kokoro to nsi to nti
Si 'lekun ayo mi o
Ti 'lekun mo 'banuje
Oba to ni kokoro to nsi to nti
Ilèkùn Ayò mí ti si
Òrun ti si 'lekun ore
Èmímímó ni alase pe ise
To da ikolo pada
Ikolo ojo pipe pada
Ikolo at'eyin wa pada
Èmímímó ni alase pe ise o
To da ikolo pada
Ilèkùn Ayò mí ti si
Jesu ti si 'lekun ore
Èmímímó ni alase pe ise
To da ikolo pada