![Eseun Oluwa](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/01/10/1ce1c292a33e4577a26af8cb50974afe_464_464.jpg)
Eseun Oluwa Lyrics
- Genre:Electronic
- Year of Release:2023
Lyrics
Ta lo da bii re Olorun to la okun pupa.
Ta lo da bii re
Olorun to rin lori okun ooo.
Ta lo da bii re
. Olorun awon olorun,
Ta lo da bii re
Emi awon wolii.
Ta lo da bii re
Olorun to ngbe nibi giga.
Ta lo da bii re
Olorun emi gbogbo eniyan.
Ta lo da bii re.....
Olorun to nje Emi ni,
Ta lo da bii re...........
Kinihun eya Judah.