Imole ft. Dhele Super Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Olu'jo mimo wa tan 'mole re fun mi o, K'emi ma se sina, K'emi ma se sise…
Olu'jo mimo wa tan 'mole re fun mi o, K'emi ma se sina, K'emi ma se sise…
Yah rah Sarah wa tan 'mole re Funmi o
Iwo ni 'mole ninu okunkun aiye…
Olu'jo mimo wa tan 'mole re fun mi o, K'emi ma se sina, K'emi ma se sise…
Olu'jo mimo wa tan 'mole re fun mi o, K'emi ma se sina, K'emi ma se sise…
Yah rah Sarah wa tan 'mole re Funmi o
Iwo ni 'mole ninu okunkun aiye…
Baba o, ma je n sina, ma je n sise
Baba o, to mi sona, Ona iye re
Baba…
Baba…
To mi sona
Baba o, ma je n sina, ma je n sise
Baba o, to mi sona, Ona iye re
Baba…
Baba…
To mi sona
Adura mi gba imole tan sona mi o
B'okunkun aiye su
B'okunkun aiye su
Imole jesu
Yo tan sona mi
B'okunkun aiye su
B'okunkun aiye su
B'okunkun aiye su
Imole jesu
Yo tan sona mi
B'okunkun aiye su
Adura mi gba imole tan sona mi o
B'okunkun aiye su
B'okunkun aiye su
Imole jesu
Yo tan sona mi
B'okunkun aiye su
B'okunkun aiye su
B'okunkun aiye su
Imole jesu
Yo tan sona mi
B'okunkun aiye su
…………………….
L'atetekose Olorun da orun oun aiye
Aiye si wa ni juu ju, o si sofo
Okunkun si wa l'oju ibu
Emi olorun si rababa l'oju omi
Lesekese olorun wa p'ase imole
Oni ki imole k'owa
Imole si wa, olorun wa ri pe o dara
Olorun p'ase Imole to Dara sinu aiye mi
K'aye mi dun Wo, k'aye mi dun ri
B'Imole ba wole, okunkun a parada o daju
Tori 'Wo ni mole ninu okunkun aiye..
Adura mi gba imole tan sona mi o
B'okunkun aiye su
B'okunkun aiye su
Imole jesu
Yo tan sona mi
B'okunkun aiye su
B'okunkun aiye su
B'okunkun aiye su
Imole jesu
Yo tan sona mi
B'okunkun aiye su
…………………………………..
Jesu kristi onimole mi
Baba jowo, ma sho mi lo
Ma se Ko mi sile, ninu irin ajo mi
Tori okunkun ngba ye kan
Jesu kristi onimole mi
Baba jowo, ma sho mi lo
Ma se Ko mi sile, ninu irin ajo mi
Tori okunkun ngba ye kan
Eni to waye tio ni jesu aiye asan lo wa
Jesu kristi ni mole tan so ninu okunkun aiye e
Eni tio ni jesu laye re okunkun biribiri lowa o
Jesu tan mole saye mi Ko wonu aiye mi lo
Bamise o baba bamise
K'emi ma fese Ko laye
Baba mimo, jowo ma sho mi lo (Baba o)
Jesu kristi onimole mi
Baba jowo, maa sho mi lo
Ma se Ko mi sile, ninu irin ajo mi
Tori okunkun ngba ye kan
Ire ni mo ni..
Mo ni
Ire ni mo mo
Mo mo
Baba jowo maa sho mi lo
Ire ni mo ni..
Mo ni
Ire ni mo mo
Mo mo…
Baba jowo maa sho mi lo
Ire ni mo ni..
Mo ni
Ire ni mo mo
Mo mo…
Baba jowo maa sho mi lo
…………………..
Jesu kristi onimole mi
Baba jowo, maa sho mi lo
Ma se Ko mi sile, ninu irin ajo mi
Tori okunkun ngba ye kan
Jesu kristi onimole mi
Baba jowo, maa sho mi lo
Ma se Ko mi sile, ninu irin ajo mi
Tori okunkun ngba ye kan
………………………