Imole Lyrics
- Genre:Acoustic
- Year of Release:2023
Lyrics
(Dandex the beat creator)
Anobi dè Imole dèee
Anobi dè Imole dèe oo
Okunkun Aiye mi odi imole kedere
Onishe nla
Anobi dè Imole dèee
Anobi dè Imole dèe oo (irawoanobi)
Okunkun Aiye mi odi imole kedere
Ode Lodimole
(Rosulullah)
Imolee
(Rosulullah)
Eniti akoko da
(Rosulullah)
Omo Aminatu
(Rosulullah)
Omo Abdullahi
(Rosulullah)
Imole o
(Rosulullah)
Anobi dè Imole dèee
Anobi dè Imole dèe oo
Okunkun Aiye mi odi imole kedere
Onishe nlã
Anobi dè Imole dèee (baarul anwaari)
Anobi dè Imole dèe oo ( Yah Rosulullah)
Okunkun Aiye mi odi imole kedere
Hudal Anbiyahii
Walil aoliyahi
Walil asfiyãhi
Ma alatkiyahi
Waliyyul walãhi
wahusnulhikahi
Wamudli shafãhi
anilashkiyãhi
Seyyidunã Muhammad n alayhi salãmu
Seyyidunã Muhammad n alayhi salãmu
Ode Lodimole
(Rosulullah)
Imolee
(Rosulullah)
Eniti akoko da
(Rosulullah)
Omo Aminatu
(Rosulullah)
Omo Abdullahi
(Rosulullah)
Imole o
(Rosulullah)
Wakhairu rojãhi
Liyaumin liqahi
Wamaolaridã
Wa ahlilwahi
Wasirru rakhãhi
Bidunibtirahi
Zuralawfiyãhi
Wa nuru ssamahi
Sanahu ssanãhi
Liratil alahi
Rosulul hayãhi wabahrul hatohii
Seyyidunã Muhammad n alayhi salãmu
Anobi dè Imole dèee
Anobi dè Imole dèe oo
Okunkun Aiye mi odi imole kedere
Onishe nla
Anobi dè Imole dèee
Anobi dè Imole dèe oo (irawoanobi)
Okunkun Aiye mi odi imole kedere
Ode Lodimole
(Rosulullah)
Imolee
(Rosulullah)
Eniti akoko da
(Rosulullah)
Omo Aminatu
(Rosulullah)
Omo Abdullahi
(Rosulullah)
Imole o
(Rosulullah)
Alambishãril maoludi
Sharil ula wasuhdadi
Sharil nnabiyyi ahmadin
Sharihu robiyil awwali
Ojo ibi anobi lotunde
Mumini muminãtu otunya
Fekantele naa ojoojumo
Aiye lo ye koshi maa jodun
Fun anobi taa be nishe si
Agbaye lapapo kaafatan
Ofi Quranu jishe pe
Tunbelohun koshike wa ni
Anobi ti kii binu
Tabawa wonu osu ti a Bii
Kiloburu kaayo katunjo
Kamuojo ibi e larinrin
Alailarojinle aawipe
Emi tio si Lanki fodun
Talori anobi fiwena
Shey eda bi daddy e lo je
Anobi tio le tan lai
Titi nio maa shemi ati
Fi aiye awa tele yanyan
Kaleba Muhammad wole ola
Ode Lodimole
(Rosulullah)
Imolee
(Rosulullah)
Eniti akoko da
(Rosulullah)
Omo Aminatu
(Rosulullah)
Omo Abdullahi
(Rosulullah)
Imole o
(Rosulullah)
Isimi anobi ni kokoro
Doodo allahu saati o daju
Otipe Timoti tenu mo
Kosiyemeji omaa gbore
Shey ifokanbale yen otiri
Idamu aiye e aadire
Botele tanobi otigba
Visa dalujannah ni kia
Ota aiye e oni roju
Foruko anobi maa jagun
Ooni kabamo kan rara
Botele tanobi teramo
Rosulullah
Imolee
(Rosulullah)
Eniti akoko da
(Rosulullah)
Omo Aminatu
(Rosulullah)
Omo Abdullahi
(Rosulullah)
Imole o
(Rosulullah)
Bosu anobi shey ko ni were
Maoludi lotun losi niomalo
Towotalafia re mãnasi
Waari pe oofi gbopo ore si
Eyin anobi aolesheytan
Titilai laoshi maa kii lo
Nabiyyul humiyyi
Anobi nuurul hudah
Imãmul murasaleena
Khaatimul anbiyahi
Imãmul muslimeenah
Seyyidul qaomi toha
Imãmul mutakeenah
Ode Lodimole anobi
(Rosulullah)
Imolee
(Rosulullah)
Eniti akoko da
(Rosulullah)
Omo Aminatu
(Rosulullah)
Omo Abdullahi
(Rosulullah)
Imole o
(Rosulullah)
Solãtullãhi thuma salãmu was'an
Alal mukhtãri nabiyyinã Muhammad
Alal mukhtãri nabiyyinã Muhammad
Alal mukhtãri nabiyyinã Muhammad