BABA KU ISE Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Baba mo ki o ku ise o
Baba mo ki o ku ise o
Ku Ise ninu aye mi
Ku Ise o, ku Ise ninu Ile mi
Ku Ise o
Opo ojo lo ti to tile to fiimu
Opo iji lol jaaa ti o gbe wa lo
Iji ja lo tun lo si to gbomi ateje
(Omi ateje)
Sebi won lo ti tan Won lo ti pari, won lo ti tan ooo, won lo ti pari
Won logo re to woomi
Won ni ko le jee yan
Sugbon Oluwa ni o je an bori
Oluwa ni o je an bori
Ku Ise ku Ise ku Ise
Baba
Ku Ise re laye mi o
Baba
Ku Ise ku Ise ku Ise o
Baba
Ku Ise re nile mi
Baba
Iwo lo gbemi soke o
Baba
Lord I give you praise, Lord I give you praise
Ku Ise ninu aye mi o
Baba
Ku Ise ninu Ile mi
Baba
Iwo lo gbogo mi jade o
Baba
Iwo lo Jo go mi o wole lol
Baba
Aye lo titan won lo ti pari o
Baba
Won logo re to wo mi o
Baba
Iwo lo fami jade kuro ninja ofin
Baba
Ku Ise ku Ise ku Ise
Baba
Baba mo ki o ooooooooo ku Ise o