Oyinkan Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2023
Lyrics
Óún níkán ló má n wú mi l'órí
Oyínkán ló má n yí mi l'órí ò
Óún níkán ló tún fún mi l'órí
Óún níkán ló má n wú mi l'órí
Nígbà tí mo n gbé ní Onírú
Tí mi l'ẹ̀fọ́, tí mi lọ́bẹ̀ Onírú
My baby baby dey dey for me
Ẹbámi dupẹ́ l'ọ́wọ́ ọmọ yìí
Pretty pretty lady
Ẹlẹ́yinjú ẹgẹ́ baby
Original African lady
Ẹyín ẹyín t'emí
Ẹbámi kírà fún baby
Onítèmi tèmi
Adúmáradán my baby
Óún níkán ló má n wú mi l'órí
Oyínkán ló má n yí mi l'órí ò
Óún níkán ló tún fún mi l'órí
Oyinkan kan
Oyinkan kan naaa
Ẹ̀yin mummy Ẹkú orí ire
Ẹ̀yin daddy adúpẹ́
Iṣẹ nlá lẹ ṣe l'órí Ọmọ
Angẹli lẹ jẹ
I promise your baby soft life
This love don dey sweeter before money enter
Óún níkán ló má n wú mi l'órí
( I can count on my baby)
Oyínkán ló má n yí mi l'órí
(Na this kain feeling make me happy)
Óún níkán ló tún fún mi l'órí
( I can count on my baby)
Oyínkán kan
Oyínkán kan naaa
Óún níkán ló má n wú mi l'órí
Oyínkán ló má n yí mi l'órí ò
Óún níkán ló tún fún mi l'órí
Oyínkán kan
Oyínkán kan naaa
Unavailable unavailable o
You're unavailable
Dem no go see you o
Unavailable unavailable o
I'm unavailable o o o ah
Óún níkán ló má n wú mi l'órí
Oyínkán ló má n yí mi l'órí ò
Óún níkán ló tún fún mi l'órí
Oyínkán kan
Oyínkán kan naaa