![Oluwa Mi Mo Njade Lo](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/09/19/9a7e684ca2bd4591ab12f83d832282e7_464_464.jpg)
Oluwa Mi Mo Njade Lo Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Oluwa mi, mo njade lo o o
Lati se ise ojo mi
Iwo nikan, le mi o mo o o
L'oro, l'ero, ati n'ise
Oluwa mi, bi mo se njade lo
S'anu funmi, ran mi l'owo
Je ki nkore oko d'ele o
K'aburu Kan ma se mi o
Go before me
Lord stay with me
And strengthen me
This Lord I pray
Iwo nikan le mi o o mo
L'oro, l'ero, ati n'ise
Iwo nikan le mi o o mo
L'oro, l'ero, ati n'ise
Oluwa mi, mo njade lo
Lati se ise ojo mi
Iwo nikan le mi o mo
L'oro, l'ero, ati n'ise
L'oro, l'ero, ati n'ise
Oluwa mi, mo njade lo
Lati se ise ojo mi
Iwo nikan le mi o mo
L'oro, l'ero, ati n'ise
L'oro, l'ero, ati n'ise
Oluwa mi, mo njade lo
Da bobo mi, la na funmi
Je ki mb'oju re re pade
K'ogo re tan yi mi ka o
K'ogo re tan yi mi ka o
Go before me
Lord stay with me
And strengthen me
This is my prayer
Iwo nikan le mi o mo
L'oro, l'ero, ati n'ise
L'oro, l'ero, ati n'ise
Yeah, mo njade lo
Hmm, mo njade lo
Asiko to la ti jade lo
Oluwa mo njade lo
Baba, ma je njade leku l'owo
Ma je njade l'arun l'owo
F'iso re so mi Oluwa
So mi lo, so mi bo
Ki ngbar'emu, d'odi mu, d'ire mu, s'ori re
Oluwa, f'ere s'ise mi,
Oluwa f'ibukun s'ise mi
Oluwa f'opo s'ise mi
Iwo nikan le mi o mo
L'oro, l'ero, ati n'ise
Iwo nikan le mi o mo
L'oro, l'ero, ati n'ise
L'oro, l'ero, ati n'ise