
Oba Ti Moni Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
Alagbara lo ba ti mo ni
O ko gbogbo aye
Si kawo re
Tani nba fi, Jesu mi we
Kosi o, rara kosi o
Alagbara lo ba ti mo ni
O ko gbogbo aye
Si kawo re
Tani nba fi, Jesu mi we
Kosi o, rara kosi o
Agbara re, ko ma la fi we
O to bi laye ati lorun
O fi ile aye ti se
O joko lori iso omi
E ba mi ki baba ku ise
O gbe mi soke, ko je ki nte
Ore Oluwa l'aye mi
Ogbon ori mi o gbe
Ah
Ife re po laye mi
Lo je ki nwa dupe
Mo r'owo re o, laye mi
Baba mo dupe dupe
Ife re po laye mi
Lo je ki nwa dupe
Mo r'owo re o, laye mi
Baba mo dupe dupe
Alagbara lo ba ti mo ni
O ko gbogbo aye
Si kawo re
Tani nba fi, Jesu mi we
Kosi o, rara kosi o
Alagbara lo ba ti mo ni
O ko gbogbo aye
Si kawo re
Tani nba fi, Jesu mi we
Kosi o, rara kosi o
Patapata Ola
Porogodo Ogo
O nile Ola
O ni te wura, Baba mi
Atogbojule
Atofarati
Iwo ni Baba
Baba ti so mi di Davidi
Omiran ti wa bi gba
O so mi di Davidi
Omiran.... O shey
Ife re po laye mi
Lo je ki nwa dupe
Mo r'owo re o, laye mi
Baba mo dupe dupe
Ife re po laye mi
Lo je ki nwa dupe
Mo r'owo re o, laye mi
Baba mo dupe dupe
Alagbara lo ba ti mo ni
O ko gbogbo aye
Si kawo re
Tani nba fi, Jesu mi we
Kosi o, rara kosi o
Alagbara lo ba ti mo ni
O ko gbogbo aye
Si kawo re
Tani nba fi, Jesu mi we
Kosi o, rara kosi o
Mo ti ri o ri
Loba ti moni
Mo tun nfeel e... Baba
Moti ri o ri...e e e
Mo tun nfeel e Baba ooo
Atobajaye Baba
Arugbo Ojo Baba
Eleruniyin Baba re
Atobajaye Baba
Atobajaye Baba
Arugbo Ojo Baba
Eleruniyin Baba re
You dey do me good oo
Atobajaye Baba
Arugbo Ojo Baba
Eleruniyin Baba re
I Love You Baba e
Atobajaye Baba
Arugbo Ojo Baba
Eleruniyin Baba re
Agbara re, ko ma la fi we
O to bi laye ati lorun
O fi ile aye ti se
O joko lori iso omi
E ba mi ki baba ku ise
O gbe mi soke, ko je ki nte
Ore Oluwa l'aye mi
Ogbon ori mi o gbe