BILLIKI Lyrics
- Genre:Soul
- Year of Release:2023
Lyrics
Ah ya Yeh shum mayoo ehm da ye
Uh mmmmm
Omo billiki iii
Oro re, o… dun mi iii
Omo billiki iii
Oro re o dun mi iii
Ìyá rẹ̀ rán ni ṣẹ́
Kò lọ pon omi lo odò
Billiki iii ko de ile mo
Ko de ile mo ooo
Ìyá rẹ̀ rán ni iṣẹ́ ehhh
Kò lọ pon omi lo odò o
Ki a tó mò biliki iii ko de ile mo
Ko de ile mo ooo
Oro billiki iii
Beng beng
Oro re, o dun mi iii
Beng beng
Omo billiki oooo
Beng beng
Oro re, o dun mi iii
Odun meje ni mo se pe
Odun mokanla, ni omo keji de
A o ṣe nkan buru si ọ
Kilode e ti e fi pa wa
E se ika buru si omode
Omọde ti o mọ nkankan
To kon sere bi omode se le se
Oro billiki o
Beng beng
Oro re, o dun mi iii
Beng beng
Omo billiki hi
Beng beng
Oro re, o… dun mi iii
Ki la lè ṣe
Kí ilẹ̀ wa ko lè dá a
Ki la lè ṣe
Ki omo wa le ṣere ni ita
Ki la lè ṣe e
Kí ilẹ̀ Africa, Kí ilẹ̀ Nigeria lè dá
Ki la lè ṣe
Ki gbogbo wa le ṣere ni ita
Ah ah ah
Omo billiki o
Beng beng
Oro re o dun mi iii
Beng beng
Omo billiki o
Beng beng
Oro re o dun mi iii
O dun mí sa ra!
O dun mí lo kon
Mí o le sa pa mo
Iya re e o shin re ti re nile
Biliki iii ko de le mo
Oh ooo Lo Jo jumo ni iya re ke
Onke e o reti one re ko dele e
Oh billiki i o sonuo
O so nuo oo
Iya re nke lojo jumo
Iiiii iiii