
Anu Re Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2023
This song is not currently available in your region.
Try the alternative versions below.
Alternative versions:
Lyrics
Anu Re - Laolu Praise
...
TITLE: ANU RE BY LAOLU PRAISE
It's can only be you God,
i give it all too you,
it's your grace.
#Ẹlomiran tiku,
ẹlòmíràn ti ṣe gbé o,
owu ọla Ọlọrun ninu ipa rẹ,
lo fifẹ rẹ bami se,
èmi erupẹ ilẹ ilẹ lásán,
lo Fáṣọ ánu rẹ bo gbogbo,
o wú ọla Olúwa o fifẹ rẹẹ, o fifẹ rẹ bami see.
chr: Aaanu rẹẹẹ, ni mo riii, iiifẹ rẹẹ ni mo ri gbaa {4ce}
led: anu eledumare
backup: Aaanu rẹẹẹ.........
led: ni mo ri ni mo ri ti mo nfi Yan
backup: ìfẹ rẹẹ.....
led: emi taba ta ka fowo ẹ́ ra tipa rẹ
backup: Aaanu rẹẹẹ ..........
led:láìsí ìfẹ rẹ kini mo jamọ óò
backup: ìfẹ rẹẹ ........
led: emi ki ni ọhun mo wa dẹni àpọ̀nlé o
backup: Aaanu rẹẹẹ ........
led: iwọ lo se yi o
backup: ìfẹ rẹẹ.............
led: ki nṣe nipa ipa tabi agbára mi óo
led: eledumare lo se ti mo nfi Yan óò
backup: Aaanu rẹẹẹ .......
ki nṣe nipa ipa tabi agbára aa
Biko se nipa anu eledumare ni oooo
mori mori mori mori
backup: ìfẹ rẹẹ .......
led: ni mori gbaa
Ogo ọla, iyin at'ẹyẹ(2ce)
ni mori gbaa, ni mori lòó
backup: Aaanu rẹẹẹ......
led: anu eledumare ni o
backup: ìfẹ rẹ ......
oju anu lẹ fi wo Josẹfu ye é
backup: Aaanu rẹẹẹ .....
led: oju anu ni mo fẹ ri gba o
backup: ìfẹ rẹ ......
led: ìfẹ lẹ fi gba Josẹfu yi o
backup: Aaanu rẹẹẹ ......
led: kini Dafidi ri gba níwájú babaaa
backup: anu rẹẹ ni mo ri gbaa
led: emi yio fi anu rẹ fún àwọn tó fẹ mi
led: ti wọn sìn nipa ọna mimọ Olúwa o
backup: ìfẹ rẹ ......
led: Anu ni mo fẹ o, anu ni mo fẹ, anu ni mo fẹ ooo, ni mo tọrọ ni mo bẹbẹ fún ooo, eledumare baba mi ooo
backup: Aaanu rẹẹẹ .......