![Eledumare by Ayandeola](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/07/20/7177aa33bb7e471dbda32b2e0ba545dc_464_464.jpg)
Eledumare by Ayandeola Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Eledumare eledumare
Eledumare eledumare
Oba wa
Oluda aye ohun orun moseba re
Toooto ola iba
Oba aiku aisa aidibaje
Paripari ola
Porogodo iyin
Ogbologbo arugbo ojo
Your grace your royalty Your excellency
Oba to jade nile seku sile Airiroara oba to ta sanmo Bi eni taso
Gbogbo agbanla aye Apoti itise re loje
Olodu to mo aare
Ayandeola oya gbe ilu Jade o je a yin eledumare
Oyigiyigi eledumare
Baba Atobajaye
Baba o akomatika lehin Eledumare a mope wa
Lord we give you glory Give you honor
Baba we exalt your holy name
Baba o akomatika lehin Eledumare a mope wa
Eledumare arugbo ojo Eleruniyin araba ribiti
Onikokoro aye lowo awa Maridi eledumare to raye Rohun Eledumare to ju aye lo
Arinirode gbanigbani akoda aye Alase laye Alase lorun
Alewilese
Aleselewi aleleleba
Alejaleso
Alesoleja
Alesileti
Aletilesi
Ibeere ati opin ohun Gbogbo
Kabiesi eledumare
Oyigiyigi oba mi
Akanaku tin migbo kijikiji
Gbanigbani lanilani
Woniwoni
Tunituni yoniyoni
Erinlakatabu erujeje Jejejejeje oba oyigiyigi Eledumare oyigiyigi Eledumare
Oyigiyigi eledumare
Baba
Atobajaye
Baba o akomatika lehin Eledumare a mope wa
Baba baba o akomatika Lehin eledumare a mope wa