
Merry Christmas Gidi ft. Vox Vitae Lma Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2019
Lyrics
Merry Christmas Gidi ft. Vox Vitae Lma - T-Sharp
...
(Drumbeats).....
Ẹlú agogo, Ẹlu agogo
Ẹlu agogo, ẹluagogo oooo
Ẹlu agogo, Ẹlu agogo
Ẹlu agogo ẹlu agogo ooo
Kérésìmesì ọdún de ooo
Kérésìmesì, ẹlu agogo
Ẹlu agogo ooooo
Go tell it on the mountain (ẹlu agogo ooo)
Yeshua saviour of the world is born (Ẹlu agogo ooo)
Àwọn Olùsọ àgùntàn , wọn sọ àgbò wọn
Ìmọ́lẹ̀ yí wọn ká
Wọ́n ní kí ló dé ó, àṣẹ olùgbàlà là bí
Olùgbàlà wa, ká àbọ̀ ooo, Ká bọ
Uh uh uh uh uh uh uh uh x2
Let me tell you about this Jesus
He's the King of the world
He's the Lord and the Saviour
He's the King of the angels
We have come to bow and worship Him
Kérésìmesì ọdún dé, Kérésìmesì ọdún dé
Ọdún de o(Òdun aà ya bo)
Kérésìmesì ọdún dé o
Ọdún Olówó , ọdún ọlọ́mọ
Ẹlu Agogo, ẹlu agogo
Ẹlu agogo ooo
Kérésìmesì ọdún dé, Kérésìmesì ọdún de
Ọdún dé, ọdún àá yà bo
Kérésìmesì (ọdún olówó) ọdún dé
Ọdún olówó ọdún ọlọ́mọ
Ẹlu agogo, Élu agogo oo
Ké re, ké re , re re re re
(Drumbeats....)
We wish you a merry Christmas
We wish you a merry Christmas
We wish you a merry Christmas
Ẹlu agogo oooo
We wish you a merry Christmas
We wish you a merry Christmas
We wish you a merry Christmas
Ẹ lú agogo ooooooo