Ounje Iye Lyrics
- Genre:Acoustic
- Year of Release:2023
Lyrics
Oun-je iye ni ara oluwa ti mo fe gba Ara Kristi at'ejere, ni mo fegba. Mo se tan o, lati je ounje iye yi o Ara Kristi at'eje re ni mo fegba.
Igbala ni, iwosan ni Idera de n'ipase ara ti mo fegba Ara at'eje oluwa, iye ma ni o Ara at'eje oluwa,iye ma ni o Ara oluwa, at'eje re Ounje iye ti o tu mi lara ( tu mi l'ara) Ounje iye ti ogbamila Ara at'ejere, iye ma nio.