Agbara Re Po ft. Olayiwola Jagun Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Alagbara nla ti momo
Oloruko nla Jesu Kristi
Olorun ton fi na dahun
Eni mimo nla Isreali
Agbara re poo
Ipa re gaaaa
Eru jeje leti okan pupa
Imole larin okunkun aye
Ko ma so hun ti ko le se
Olagbara ju aye lo.
Olorun to gba omo heberu ninu ina eleru
Olagbara ju ogun aye re
Wa yayo isegun
Agbara re poo
Ipa re gaaaa
Eru jeje leti okan pupa
Imole larin okunkun aye
Ko ma so hun ti ko le se
Olagbara ju aye lo
Oriki
Ayeraye olorun otitooo
Ijinle ife, olorun ododo
Oba ako magbe ka leyin
Oba moni mana, oba mana moni
Oba tolo kanrin
Kese
Oba to baye leru bi ara sisan, ogbagba ti
Se alpha ati omega,eni isaju ati eni ikeyin
Oni kokoro aye lowo ooo
Oba to pa ti enikan o le ji laye
Oba ton ji ten ikan ole pa
Okiki ara daru bo okunkun mole
Giga giga to ju awon oke lo
Oba to wo Jerusalem pelu awon amin nlala
Agbara to gbe wokabelamu keremi ko
Oni se iyanu oooo, iyanu iyanu lofi ya gbogbo araye lenu
Alabgara ton gba agbara lowo alagbara ton fi agbara nini lara
Oba mi oke baba agba oooo
Agbara re pooo
Ipa re gaaaa
Eru jeje leti okan pupa
Imole larin okunkun aye
Ko ma so hun ti ko le se
Olagbara ju aye lo