
Morning Devotion 1 Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2019
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Morning Devotion 1 - EmmaOMG
...
Good morning Jesus
Good morning Lord
I know you came from heaven above
The Holy Spirit is in the throne
Good morning Jesus
Good morning Lord...
Good morning Jesus
Good morning Lord
I know you came from heaven above
The Holy Spirit is in the throne
Good morning Jesus
Good morning Lord
Mo sun l'ayọ, mo jí l'ayọ
Mo f'ogo f'Oluwa
Mo jí l'ayọ, Baba mo dupẹ oo
Mo sun l'ayọ, mo jí l'ayọ
Mo f'ogo f'Oluwa
Mo jí l'ayọ, Baba mo dupẹ oo
See I slept and I woke up
Because God kept me
Mo jí l'ayọ, Baba mo dupẹ oo
Mo sun l'ayọ, mo jí l'ayọ
Mo f'ogo f'Oluwa
Mo jí l'ayọ Baba mo dupẹ oo
I will enter His gates with thanksgiving in my heart
I will enter His courts with praise
I will say this is the day that the Lord has made
I will rejoice for He has made me glad. Ah.. Ah..
He has made me glad
He has made me glad
I will rejoice for He has made me gla...d
He has made me glad
He has made me glad
I will rejoice for He has made me glad
O ṣe Jesu t'O f'ifẹ ńlá dá mi si
Ọpọlọpọ lọ tí kú tí wọ́n ti f'ilẹ bora
Owu Oluwa n'nu anu Rẹ, tó f'ifẹ ńlá da mi si
Ògo ìyìn ọlá, lọ yẹ Ọ Messiah
O ṣẹ Jesu t'O f'ifẹ ńlá dá mi si
Ọpọlọpọ lọ tí kú tí wọ́n ti f'ilẹ bora
Owu Oluwa n'nu anu Rẹ, tó f'ifẹ ńlá da mi si
Ògo ìyìn ọlá, lọ yẹ Ọ Messiah
Thank You Jesus, Thank You my Lord
Whatever I am now, it is by your Grace
Many are dying, many are perishing
Whatever I am now, it is by your Grace
Thank You Jesus, Thank You my Lord
Whatever I am now, it is by your Grace
Many are dying, many are perishing
Whatever I am now, it is by your Grace
Jìjì mo jí o Baba
Mo wà f'opẹ fún Ọ
Mo sun l'ayọ, mo jí l'ayọ
Mo wa yin Ọ l'ogo
Jìjì mo jí o Baba
Mo wà f'opẹ fún Ọ
Mo sún l'ayọ, mo jí l'ayọ
Mo wa yin Ọ l'ogo
In the morning, early in the morning
In the morning I will rise and praise the Lord, Hallelujah
In the morning, early in the morning
In the morning I will rise and praise the Lord
Ọpẹ l'O yẹ Ọ, Baba oloore
Ìyìn l'O yẹ Ọ, Ọlọ́run Ọba
Hosanna yẹ Ọ, O ṣe O Baba
Ọpẹ l'O yẹ Ọ, Baba oloore
Ìyìn l'O yẹ Ọ, Ọlọ́run Ọba
Hosanna yẹ Ọ, O ṣe O Baba
Anytime I see another breaking of day
I say Thank You Lord, Thank You Lord
Every time I see another breaking of day
I say Thank You Lord, Thank You Lord
(Every time)
Every time I see another breaking of day
I say Thank You Lord, Thank You Lord
Every time I see another breaking of day
I say Thank You Lord, Thank You Lord
Say Jesus (Jesus) oh Jesus (Jesus)
How I love... How I love... calling Your Name
Darling Jesus (Jesus) Jesus (Jesus)
Every day Your Name is the same
Say... How I love calling Your Name
'Cos every day Your Name is the same
How I love.. calling Your Name
Every day Your Name is the same
How I love... How I love calling Your Name
Every day.. Your Name is the same
Say how I love calling Your Name
Every day Your Name is the same
Say how I love... How I love to calling Your Name
Every day Your Name is the same
O ṣẹ O Jesu, O ṣẹ O Baba
Ipò tí mo wà, ore-ọfẹ Rẹ ni
Ọpọ lo tí kú ó, Ọpọ lo tí ṣ'egbe
Ipò tí mo wà, ore-ọfẹ Rẹ ni
O ṣẹ O Jesu, O ṣẹ O Baba
Ipò tí mo wà, ore-ọfẹ Rẹ ni
Ọpọ lo tí kú ó, Ọpọ lo tí ṣ'egbe
Ipò tí mo wà, ore-ọfẹ Rẹ ni
Olufẹ ọkan mi, ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
Olufẹ ọkan mi, ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
Olufẹ ọkan mi, ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
Olufẹ ọkan mi, ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
Olufẹ ọkan mi, ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
You're the lover of my soul, yeah, ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
Ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
Olufẹ ọkan mi, ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
Ololufẹ mi ni Jesu oo, ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
Ó ti fẹ mi k'ọ to bí mi oo...ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
Ifẹ at'ọkan wa l'O ni sì mi, unconditional, ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
So.. mo fẹran Rẹ pada o.. ma k'ọrin ma gbe Ọ ga
His mercies are new every morning, new every morning
Great is Thy faithfulness O Lord
Great is Thy faithfulness O Lord
Great is Thy faithfulness O Lord
Great is Thy faithfulness O Lord
That's why the heavens declare your glory
Great is Thy faithfulness O Lord
The firmament show off your handiworks
Great is Thy faithfulness
Day after day, your work speaks... Great is Thy faithfulness O Lord
Night after night showeth knowledge yeah..
Great is Thy faithfulness
Ìró wọn là gbogbo aye ja ooo
Wọn ní pe Baba, Ẹ ṣe O Baba
Ẹ ṣe O Baba, àwa dupẹ Baba
Baba, Baba, Baba
Baba, Ẹ ṣe O Baba
Ẹ ṣe O Baba, àwa dupẹ Baba
Fun dida t'Ẹ da wa si o
Baba, Ẹ ṣe O Baba
Ẹ ṣe O Baba, àwa dupẹ Baba
A dupẹ ooo.. A dupẹ oooo
Oh my God...