
Iranlowo Mi Lyrics
- Genre:Spirituals
- Year of Release:2023
This song is not currently available in your region.
Try the alternative versions below.
Alternative versions:
Lyrics
Iranlowo Mi - Hemhem
...
iranlowo mi olugbeja mi
oju mi n wo O
Jesu jewo Ara re
mo ti gboju mi soke
sibi iranlowo
iranlowo mi nbe
lowo Oluwa
oun ki o je ke mi subu
oju ko mi ti mi laelae
Apata ti ki ye
lolorun ti mo feyin ti
Jesu jewo Ara re
Chrs
Bi agbonrin ti n mi hele
si ipado Omi
okan mi n mi hele si o
olorun iranlowo
Iwo ni ireti Iwo ni gbekele mi
ma se ja mi kule
gba mi o gba mi o
agbani ma gba ni ti
lolorun ti mo gbojule
Jesu jewo ara re
chrs
bridge
awa to duro doluwa
a o run agbara wa se
a o sare ki yo si re wa
a o fi ye goke bi idi
a o ri are ki yo mu wa
a ti re ni gbojule
awa ti ri baba gbojule
awa ti ri baba foro lo
gba ni gba ni la ni la ni
yo ni yo ni
olorun iranlowo nbe fun wa
eee a
awa ti ri baba gbojule
call: mo gboju si olorun
res: iranlowo