![Táǹwá](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/06/28/262289cb300b46d4a7e993a71ae16425_464_464.jpg)
Táǹwá Lyrics
- Genre:Blues
- Year of Release:2023
Lyrics
Táǹwá - The Musical Being
...
Ọjọ' ńlọ Ìgbá ńkọjá
Ẹ'dá ń lògbà, Ìgbá ń dẹwá
Àlowónlé ń sáre ọlá oo
Bọ'lanlé ń sáre owó oo
Àrídunúu ń sukún w'ayọ'
Iyọ' ń wá'dún oyin
Elédùà Elédùà
Mo ṣ'àduà wípé
Ìràwọ' mí átan
Àlá 're áṣee, ah
Ǹkán árọgbọ l'ọọ'dẹ' wá
Àgàn átọwọ' àlàbosùn
Àáoríre Tàńwá
Ìràwọ' mí átan
Àlá 're áṣee
Ǹkán árọgbọ l'ọọ'dẹ' wá
Àgàn átọwọ' àlàbosùn
Àáoríre Tàńwá
Ajé
Jémi ní'pè
Ojúmọ' túntimọ'
Jé n rítèmi ṣe
Ọmọdé yii fẹ' dàgbà
Àgbá fẹ' yígbà d'àpọ'n
'Lédùà mà ṣemí l'ádán
Tó n f'ọ'san wò'ṣe ẹiyẹ ò
Mà mà jẹ' n ṣiṣẹ' bí erin
Kin jẹ"jẹ èlírí
Mo gbóùn sókè
Mo ṣ'àduà wípé
Ìràwọ' mí átan
Àlá 're áṣee
Ǹkán árọgbọ l'ọọ'dẹ' wá
Àgàn átọwọ' àlàbosùn
Àáoríre Tàńwá
Ìràwọ' mí átan
Àlá 're áṣee
Ǹkán árọgbọ l'ọọ'dẹ' wá
Àgàn átọwọ' àlàbosùn
Àáoríre Tàńwá
Chant
Ìràwọ' mí átan
Àlá 're amáṣee (amin)
Ǹkán árọgbọ l'ọọ'dẹ' wá
Àgàn átọwọ' àlàbosùn
Àáoríre Tàńwá
Ìràwọ' mí átan
Àlá 're áṣee
Ǹkán árọgbọ l'ọọ'dẹ' wá
Àgàn átọwọ' àlàbosùn
Àáoríre Tàńwá