Damilohun Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2020
Lyrics
Iwo nikan lole gbami o eh eh
Iwo nikan lole gboro mi ro baba o
Mo wole niwaju re mo kepe o baba jowo
Aiye ti nbere wipe ibo ni ngo gbe gba
Ona tomi ba wo agbon se bi iwo lo le so olorun
Damilohun Damilohun Damilohun mo fe gbe gba ope o
Damilohun Damilohun Damilohun mo fe gbe gba ope o
Eni ba wo iseju akan a pe leti omi
Olorun igba to mase ma ma je ko ye won
Je kan ma waa kiri ona to mi ba won nu agbo
Bo se se o ko seni to mo iwo loye
Eh eh o eh eh o Oluwa
IIekun ayo yen t'i ota ro bawon tii
Eledunmare baba dakun bami shi
Tiwon ba npe oloriire edunmare je kin number 1
Kodun kopo ko pe o
Damilohun lohun lohun o
Damilohun Damilohun Damilohun mo fe gbe gba ope o
Damilohun Damilohun Damilohun mo fe gbe gba ope o
Asiri eko koni tu loju ewe olorun mi damilohun
Igba to ma se ma je koye ota mii
Je kan beere se emi ni abi emi ko
Loju abinu eni baba dami lohun
Leta ayo fi lemi lowo
Jekaraye beere pe se Olorun kan ni
Abi olorun naa ko lo se beebe laiye wa
Hnmm hnmm hnmm hnmm hnmm
Damilohun mofe gbe gba ope o oo
Damilohun Damilohun Damilohun mo fe gbe gba ope o
Damilohun Damilohun Damilohun mo fe gbe gba ope o
O sha ti mon mi pe ngo lenikan afi iwo olorun mi
Abudi ni tolokun abudi ni t'olosa
Tori mon sin o mi o gbodo t'awona
Edunmare damilohun o
Aiye tin bere pe ibo ni ngo gbe gba
Oro mi ni won so kiri o eh
Won lojojumo lon re church lo sin olorun
Remilekun olorun o
Adura ti mo gba kele kele
Damilohun lohun lohun o
Kaye le ma royin ise owo re
Je nkore dele
Je nkore dele
Gbogbo ilakaka mi lori gun mererin agbanla aiye
Atobiju olorun mi
Je nkore dele
Je nkore dele
Da pada da pada
Edunmare bami da pada gbogbo ire ti ota gba lowo mi o
Eledunmare baba dawon pada oo
Ire gusu ire ariwa ire ila orun iwo orun
Gbogbo ibikibi ti mo laagun de olorun
dawon pada simi lowo o
Kin gbe gba ope olorun ti a da pada
Edunmare bamida pada
gbogbo ire ti ota gba lowo mi o
Eledunmare baba dawon pada oo
Emi a gboju mi sori oke wonni
Nibo ni iranlowo mi yio ha ti wa
Iranlowo mi yio t'owo olorun wa
Eni tio da orun ohun ati aiye
Eni ti pami mon kii sun beni kii togbe
Eni ti pa isreali ki sun rara
Ohun ni o se alabo mi
Mo claim eh
Ire
Ire
Ire