
Wón SÍNWÍN Lyrics
- Genre:Highlife
- Year of Release:2023
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Wón SÍNWÍN - Jeje Rhythms
...
Wón ti SÍNWÍN ri
Walahi, Wón ti SÍNWÍN ri
Wón ti SÍNWÍN ri
So o mo pon to SÍNWÍN ri
Awon to ni ibo la o gbe GBA
Wón ti SÍNWÍN ri
Awon to n wa subu wa o
Won ya were ri o
Chorus
Wón ti SÍNWÍN ri
Walahi, Wón ti SÍNWÍN ri
Wón ti SÍNWÍN ri
Walahi won ti SÍNWÍN ri
Awon to ni ibo la o gbe GBA
Wón ti SÍNWÍN ri
Awon to n wa subu wa o
Won ya were ri o.
Won ti SÍNWÍN ri,
So mo pon ti San Lori
Won ti f'ori GBA, won o pari abere
Ogun Aaro o, na lo n lo lale
Ohun tan ni kan Fi we, ni won n gbemu
Awon to ni ibo la o gbe GBA
Wón ti SÍNWÍN ri
Awon to n wa subu wa o
Won ya were ri o.
Chorus
Wón ti SÍNWÍN ri
Walahi, Wón ti SÍNWÍN ri
Wón ti SÍNWÍN ri
Walahi won ti SÍNWÍN ri
Awon to ni ibo la o gbe GBA
Wón ti SÍNWÍN ri
Awon to n wa subu wa o
Won ya were ri o.
Se ri won, se n wo won o
Se ri won, pe won o mo n tan se
A ri won, a ti da won mo ,
A ri won pe won o mo n tan se.
Se ri won, bon se n b'Olorun ja o
Se ri won, won wo seju akan
A Le ku si won, Ejo ni won le pada o
Se ri won, pe won o mo n tan se
A ri won, a ti da won mo ,
A ri won pe won o mo n tan se.
Chorus
Wón ti SÍNWÍN ri
Walahi, Wón ti SÍNWÍN ri
Wón ti SÍNWÍN ri
Walahi won ti SÍNWÍN ri
Awon to ni ibo la o gbe GBA
Wón ti SÍNWÍN ri
Awon to n wa subu wa o
Won ya were ri o.
Talking Drums
Olote ni o j'egba,
Olote ni o j'egba,
A jiya, a jewe iya
Olote ni o j'egba,
Abamo ni o gbeyin won
Abamo ni o gbeyin won
Won se'ka, won f'ori ko'mi
Abamo ni o gbeyin won.
Se ri won, se n wo won o
Se ri won, pe won o mo n tan se
A ri won, a ti da won mo ,
A ri won pe won o mo n tan se.
Wón ti SÍNWÍN ri
Walahi, Wón ti SÍNWÍN ri
Wón ti SÍNWÍN ri
Walahi won ti SÍNWÍN ri
Awon to ni ibo la o gbe GBA
Wón ti SÍNWÍN ri
Awon to n wa subu wa o
Won ya were ri o
Wón ti SÍNWÍN ri
Walahi, Wón ti SÍNWÍN ri
Wón ti SÍNWÍN ri
Walahi won ti SÍNWÍN ri
Awon to ni ibo la o gbe GBA
Wón ti SÍNWÍN ri
Awon to n wa subu wa o
Won ya were ri o... Till fade