Keresimesi ti De ft. Adeboye Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2023
Lyrics
Adupẹ o Baba
Adupẹ o Jesu
Adupẹ o Baba
Adupẹ o Jesu
Keresimesi
Keresimesi
Ti de o
Awa juba
Fun ọ Jesu
Keresimesi
Keresimesi
Ti de o
Olugbala Kristi de o
Atiri irawọ ogo
Keresimesi
Idunnu siti ku aye
Ayọ kun ọrun o
Abi Jesu Olugbala
Imanueli o
Awọn angeli n k'ọrin ayọ
Keresimesi ti de o
Adupẹ o Baba
Adupẹ o Jesu
Adupẹ o Baba
Adupẹ o Jesu
Keresimesi
Keresimesi
Ti de o
Awa juba
Fun ọ Jesu
Keresimesi
Keresimesi
Ti de o
Olugbala Kristi de o
Ẹk'ọrin Aleluya
Alade ogo ti de
Ẹk'ọrin Aleluya
Alade ogo ti de
Ọba ti de
Ọba awọn ọba
Jesu
Ọba ti de
Ọba awọn ọba
Jesu Kristi
Ka juba fun Ọba
Olugbala ti de
Ka juba fun Ọba
Ẹk'ọrin Aleluya
Ka juba fun Ọba
Olugbala ti de
Ka juba fun Ọba
Ẹk'ọrin Aleluya o
Olugbala wa kaabọ
Olugbala wa ti de
Olugbala wa kaabọ o
Ẹse o Ẹmi Mimọ
Ẹ bá wa kí Ọba wa Kú àbọ̀
Ọba
È é é
Àgbàlagbà ìgbàanì
Ọba kọnrin kese kese Kọnrin
Ọba ọlọkan funfun
Aláwọ̀ funfun
Onímọ̀ funfun
Aládé funfun
Kú abọ
A n wa a n wa a n wa a n wa
Ẹmi mimọ nirawọ
A ti rin a ti rin a ti rin rin rin
Irawọ lo gbewa de
A gbagbọ ninu Mesaya
Adari gbo gbo ẹda
Ni bẹtẹlẹhẹmu la ti bi
Olugbala yi o
Atiri irawọ rẹ o
O si n dan yan yan ni
Ibukun ni fun Mariya
Iya Ọba igbala
Ọpẹ ọpẹ ni fun Josefu
To duro ti imọlẹ wa
Nibugbe ẹran latiri
Ọba ogo
Keresimesi ti de
Olugbala wa de
Irapada awa ti de o
Oṣe Jesu o
Oṣe Jesu
Kabiyesi sí oò
Oluwa
Awa juba
Kaabọ o
Ehh Kabiyọ o si oo
Eledumare to dáwà si eledua awa
Ọbani
E é e
Ọbani
Ahaaa
Ọbani o
Ọba àwọn ọba káàbọ ooo