Greater Is He Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Greater Is He - Min. Oluwaferanmi
...
Enito ngbe inu mi, oju aye ati orun lo
Baba to ngbe inu mi, oju aye ati orun lo
Koku oo, beni kosun, ipa to bori ipa
Koku oo, beni kosun, inumi lofi se ibugbe
Enito ngbe inu mi, oju aye ati orun lo
For the greater is he that is in me,
I say greater is he that is in me than that is in the world
Oju aye ati orun lo baami ni
Atofarati
Oju aye ati orun lo baami ni ehh
Greater is he that is in me, than he that is in the world
Beats………………………
Otobi pupo aye ati orun koma gba seh
Ninu oun gbogbo ti o da, emi loyan lati fe se ile re.. Ofi mi sele oo
O ngbe ninu mi oo, aditu ni sir
Kose fenu so
Greater is he that is in me oo.. 2ce
Enito gbe nu mi, oju aye ati orun lo
Baba tongbe nu mi, oju aye ati orun lo
Koku oo beni kosun, ipa to bori ipa
Koku oo beni kosun, inu mi lofi se ibugbe
Eni tongbe inu mi, oju aye ati orun lo
Hymn…….
Bibeli mi fi ye mi momo odami loju
Eda oto nimi, olu alufa iran ti ayan
Lati inu mi oo, omi iye nsan ti kole gbe lailai
Greater is he that is in me oo
Eni tongbe inu mi, oju aye ati orun lo
Baba tongbe inu mi, oju aye ati orun lo
Koku oo beni kosun, ipa to bori ipa
Koku oo beni kosun, inu mi lofi se ibugbe
Eni to ngbe inu mi, oju aye ati orun lo
Toluwa nile atekun re
Aye atekun nure
Ofi dire sole lori okun
Ati lori isan omi
Gboriyin soke, eyin ilekun
Kagbe yin soke, ko oba ogo wole wa
O wonu mose, akalolo ofi mi egypti
O wonu peteru apeja wa sise igbala kiri
Se e ogbagbe dafidii, omo ijosi topa goliathi
Ongbe ninu mi oo, satani ma ta fele fele kiri
Eni tongbe inu mi, oju aye ati orun lo
Baba tongbe inu mi, oju aye ati orun lo
Koku oo beni kosun, ipa to bori ipa
Koku oo beni kosun, inu mi lofi se ibugbe
Eni to ngbe inu mi, oju aye ati orun lo