- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
AMIN - BUKOLA & DAMILOLA BEKES
...
Instrumental
Amin beeni kori oo
Amin mo gba leta ayo
Amin ire gbogbo wole mi wa
Amin ooo
Hallelujah
Amin beeni kori oo
Amin mo gba leta ayo
Amin ire gbogbo wole mi wa
Amin ooo
Hallelujah
Amin beeni kori oo
Amin mo gba leta ayo
Amin ire gbogbo wole mi wa
Amin ooo
Hallelujah
Instrumental
Jesu ni ka bere ,ohun yo fi fun wa
Oni ki a kan lekun, ohun yo si fun wa
oni kepemi nigba iponju
Iwo sha ti fi gbagbo ro Mon
Asee se
Jesu ni ka bere ,ohun yo fi fun wa
Oni ki a kan lekun, ohun yo si fun wa
oni kepemi nigba iponju
Iwo sha ti fi gbagbo ro mon
Asee se
Amin
Amin beeni kori oo
Amin mo gba leta ayo
Amin ire gbogbo wole mi wa
Amin ooo
Hallelujah
Alabukun ni fun ooo
Amin
Oju asegun lo ooo
amin
Yio Dara fun o ooo
Amin, Hallelujah
Ibunkun ni fun agbon re
Amin
ibunkun ni fun eka re
Amin
Ibunkun ni fun eso inu re oo
Amin, Hallelujah
ijade re ire ni oo
Amin
iwole re ire ni oo
Amin
Yio dara fun o oo
Amin, Hallelujah
monipe dide ki o tan imole
toripe imole re de
Ogo oluwa yo lara re ee
Amin, hallelujah
won o ni bo Bata ofo senu ona ile yin
amin
oke oke le o ma lo ooo
Amin
yio dara fun o ooo
Amin, hallelujah
gbogbo ohun ti e dawole ayorisi rere oo
Amin
Oke oke le o ma lo o
Amin
Yio dara fun o ooo
Amin, hallelujah
Alabukun ni fun o ooo
Amin
loruko jesu
amin
Yio Dara fun o ooo
Amin, hallelujah
Alabukun ni fun o ooo
Amin
loruko jesu
amin
Yio Dara fun o ooo
Amin, hallelujah
Alabukun ni fun o ooo
Amin
eh eh eh eh eh
amin
eh eh eh eh
Amin, hallelujah
instrumental