Momo Jesu Remix (feat. Prince Goke Bajowa) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Ore bi ti Jesu, kosi ninu aye yi
Owa saye ese Yi, osi ku fun ese mi
Olugbejami loje, sohun lore otito
Jesu gbamila, otun ayemi se
I love the man of Galilee, He's done so much for me
He set me free, he saved my soul, and he gave me eternal life
So I will live forevermore with him in paradise
Jesu gbamila, otun ayemi se
Momo Jesu,
Alagbara ni Jesu
Do you remember the man, by the pool of Bethesda
He was sick for thirty eight years and he had no help at all
So when the Lord, Jesus came around, Jesus made him whole
Jesu gbamila, otun ayemi se
Lasaru jadewa, beeni Jesu wi
Oku totiku fun ojo merin, ogbo osi jinde
Agbara toji oku lasaru, sohun lo fowo kanmi
Jesu gbamila, otun ayemi se
Momo Jesu
Alagbara ni Jesu
Bridge:
Ololufe mi, olugbe orimi soke
Agbanilagbatan o, sa loje o
Ife Okan mi sa leje o
Asore maseregun o
Eyin lopomulero, ayemi o
Oba Lori aye gbogbo
Iwo nikan lemi o masin
Iwo loje kayemi ko nitumo o
Agbara re ju gbogbo aye lo
Oruko re ti niyin to o
Iwo ni aterere Kari aye
Momo Jesu
Alagbara ni Jesu.