Godfidence Xtra Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Mo ti ni Jesu
_Mo ti ni_
Emi o jisoro
_Mo ti ni_
Aya o fo mi mo
_Mo ti ni_
Omo Baba ni mi
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Eni ba ti ni Jesu
_So ti ni?_
Ko ni lati jisoro
_So ti ni?_
Aya o le fo e mo
_So ti ni?_
To r'omo Baba ni e
_So ti ni?_
F'aye re fun Jesu
_So ti ni?_
F'aye re fun Jesu
_So ti ni?_
Mo ti ni Jesu
_Mo ti ni_
Emi o jisoro
_Mo ti ni_
Aya o fo mi mo
_Mo ti ni_
Omo Baba ni mi
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Se o ti ni Jesu?
_So ti ni?_
Se o ti l'Oluwa?
_So ti ni?_
Ninu aye re?
_So ti ni?_
S'omo Baba ni e?
_So ti ni?_
Ara mi o lewu
_So ti ni?_
T'o baini Jesu
_So ti ni?_
Mo ti ni Jesu
_Mo ti ni_
Emi o jisoro
_Mo ti ni_
Aya o fo mi mo
_Mo ti ni_
Omo Baba ni mi
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Ẹniti o joko ni ibi ìkọkọ Ọga-ogo ni yio ma gbe abẹ ojiji Olodumare.
Emi o wi fun Ọlọrun pe, Iwọ li àbo ati odi mi; Ọlọrun mi, ẹniti emi gbẹkẹle.
Nitõtọ on o gbà mi ninu ikẹkun awọn pẹyẹpẹyẹ, ati ninu àjakalẹ-àrun buburu.
Yio fi iyẹ́ rẹ̀ bò mi, abẹ iyẹ́-apa rẹ̀ ni emi o si gbẹkẹle: otitọ rẹ̀ ni yio ṣe asà ati apata mi.
Emi kì yio bẹ̀ru nitori ẹ̀ru oru; tabi fun ọfa ti nfo li ọsán;
Tabi fun àjakalẹ-àrun ti nrìn kiri li okunkun, tabi fun iparun ti nrun-ni li ọsángangan.
Ẹgbẹrun yio ṣubu li ẹgbẹ mi, ati ẹgbarun li apa ọtún mi: ṣugbọn kì yio sunmọ ọdọ mi
Kiki oju mi ni iwọ o ma fi ri, ti o si ma fi wo ère awọn enia buburu.
T'o ba ti ni Jesu
_So ti ni?_
Esu kan le ma hale
_So ti ni?_
Ko le bori re
_So ti ni?_
Eni to ngbenu re
_So ti ni?_
O ju taye lo
_So ti ni?_
Okan re a bale
_So ti ni?_
To ba ti ni Jesu
_So ti ni?_
Mo ti ni Jesu
_Mo ti ni_
Emi o jisoro
_Mo ti ni_
Aya o fo mi mo
_Mo ti ni_
Omo Baba ni mi
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_